Xanana Gusmão
Kay Rala Xanana Gusmão GCL (oruko abiso José Alexandre Gusmão, ojoibi 20 June 1946) je alagidi ogun tele to di Aare akoko ile Ilaorun Timor, lori aga lati May 2002 de May 2007. Leyin re o tun di Alakoso Agba ile Ilaorun Timor ni 8 August 2007 titi doni.[1]
Xanana Gusmão | |
---|---|
Prime Minister of East Timor | |
Lọ́wọ́lọ́wọ́ | |
Ó gun orí àga 08 August 2007 | |
Ààrẹ | José Ramos-Horta Vicente Guterres (Acting) Fernando de Araújo (Acting) José Ramos-Horta |
Asíwájú | Estanislau da Silva |
President of East Timor | |
In office 20 May 2002 – 20 May 2007 | |
Alákóso Àgbà | Mari Alkatiri José Ramos-Horta Estanislau da Silva |
Asíwájú | Sérgio Vieira de Mello |
Arọ́pò | José Ramos-Horta |
Àwọn àlàyé onítòhún | |
Ọjọ́ìbí | 20 Oṣù Kẹfà 1946 Manatuto, Portuguese Timor |
Ẹgbẹ́ olóṣèlú | CNRT |
(Àwọn) olólùfẹ́ | Emilia Batista Gusmão (1965 - 2000) Kirsty Sword Gusmão (2000 - present) |
Occupation | Military Politician |
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |
Itokasi
àtúnṣe- ↑ "Gusmao sworn in as East Timor PM", Al Jazeera, 8 August 2007.