Xu Qing (Àdàkọ:Zh; tí wọ́n bí lọ́jọ́ kejìlélógún oṣù kìíní ọdún 1969),[1] tí a tún mọ̀ sí Summer Qing,[2] jẹ́ gbajúmọ̀ Òṣèrébìnrin ọmọ China. Wọ́n gbà á sí ilé-ẹ̀kọ́ sinimá Beijing Film Academy lọ́dún 1988, ó sìn kẹ́kọ̀ọ́ jáde lọ́dún 1992.[3]

Xu Qing
Ọjọ́ìbí22 Oṣù Kínní 1969 (1969-01-22) (ọmọ ọdún 55)
Beijing, China
Iléẹ̀kọ́ gígaBeijing Film Academy
Iṣẹ́Òṣèrébìnrin
Ìgbà iṣẹ́1990–títí di àsìkò yìí
AgentHuayi Brothers
Xu Qing Studio
Àdàkọ:Infobox Chinese/HeaderÀdàkọ:Infobox Chinese/ChineseÀdàkọ:Infobox Chinese/Footer

Iṣẹ́

àtúnṣe

Ọdún 1999 ni Xu kọ́kọ́ jáde nínú sinimá kan tí àkọlé rẹ̀ ń jẹ́ made Life on a String, tí Chen Kaige darí. Wọ́n yàn án lọ́dún 1992 fún ami-ẹ̀yẹ Hundred Flowers Award for Best Actress nítorí ipa tó kó nínú sinimá Ripples Across Stagnant Water. Lọ́dún kan náà, ó tún di ìlúmọ̀ọ́ká sí ní gbogbo China nínú eré orí tẹlifíṣàn kan tí wọ́n ń pè ní At the Foot of The Imperial City

Lọ́dún 2001, ó tẹ̀ síwájú nínú iṣẹ́ rẹ̀ lẹ́yìn tó kópa nínú eré Ren Yingying tí wọ́n máa ń ṣàfihàn lórí tẹlifíṣàn, Laughing in the Wind (2001).[4]

Lọ́dún 2003, Xu gbàmì-ẹ̀yẹ Audience's Choice for ActressChina TV Golden Eagle Award fún ipa tó kó nínú sinimá kan tí ó ti kópa gẹ́gẹ́ bí ọ̀tẹlẹ̀múyẹ́, The Chinese Woman at the Gunpoint of Gestapo.[5]

Lọ́dún 2009, Xu kópa gẹ́gẹ́ bí Soong Ching-ling nínú sinimá ìtàn ìṣẹ̀dálẹ̀ Àwọn China tí wọ́n pè ní The Founding of a Republic,[6], sinimá yìí ló mú un gba ami-ẹ̀yẹ amúgbalẹ́gbẹ̀ẹ́ Òṣèrébìnrin tó dára jù lọ ní Macau International Movie Festival àti Hundred Flowers Awards.[7][8] Ní ọgbọ́n ọjọ́, oṣù kọkànlá ọdún 2009, wọ́n gba Xu gẹ́gẹ́ Òṣeré fún fún ètò awáràwọ̀ Huayi Brothers.[9]

Lọ́dún 2010, ó tún ṣe dáadáa nínú sinimá ìfẹ́ kan tí wọ́n pè ní Blossoming of Beautiful Flowers, tí Gao Xixi.[citation needed] gbé jáde.

Lọ́dún 2012, ó kópa gẹ́gẹ́ bí ìyàwó Bruce Willis nínú sinimá Amẹ́ríkà tí wọ́n pè ní Looper.[10]

Lọ́dún 2013, Xu gba ami-ẹ̀yẹ Huading Awards gẹ́gẹ́ bí Òṣèrébìnrin tó dára jù lọ nítorí ipa tó kó nínú eré orí-ìtàgé tí wọ́n pè ní A Dream Like A Dream.[11]

Lọ́dún 2016, Xu tún di gbajúmọ̀ sí i nínú sinimá ọ̀ràn dídá kan tí wọ́n pè ní Mr. Six,[12] which won her the Hundred Flowers Award for Best Actress award.[13]

Lọ́dún 2017, Xu tún gbajúmọ̀ sí i nínú ọgbójú sinimá Gúúsù Amẹ́ríkà àti Áfíríkà tí wọ́n pè ní 24 Hours to Live.[14]

Àtòjọ àwọn sinimá rẹ̀

àtúnṣe
Odun Àkọlé lédè òyìnbó Àkọlé lédè China Ipa àkíyèsí
1990 Life on a String 边走边唱 Lan Xiu'er
1992 Ripples Across Stagnant Water Cai Dasao
1994 Dark Obsession 疯蝶 Ai Mei
1996 The Emperor's Shadow 秦颂 Princess Yueyang
1999 Agreed Not to Separate 说好不分手 Lin Qiao
1999 My 1919 我的1919 Mei
2007 Flash Point 导火线 Madam Lau Cameo[15]
2009 The Founding of a Republic 建国大业 Soong Ching-ling
2012 To My Wife 与妻书 Chen Yiyang / Xia Shan [16]
2012 Looper 环形使者 Old Joe's wife Credited as "Summer Qing"
2015 I Love You, Too. 恋爱排班表 Xiao Qi [17]
2015 Mr. Six 老炮儿 Hua Xiazi
2016 League of Gods 封神传奇 Taiyi Zhenren [18]
2017 24 Hours to Live 24小时:末路重生 Lin
The Hidden Sword 刀背藏身 Zhihui [19]
2018 Hidden Man 邪不压正 Tang Fengyi [20]
TBA Song of the Assassins 刺局 Madame Hua [21]
TBA Confidant 士为知己者 [22]
TBA Silence of Smoke 闻烟 [23]

Eré orí tẹlifíṣàn

àtúnṣe
Odun Àkọlé lédè òyìnbó Àkọlé lédè China Ipa àkíyèsí
1991 Nanxing Ji 南行记 Yemaozi
1992 At The Foot of the Imperial City 皇城根儿 Jinzhi
1993 The Witty Advisor 金牌师爷 Princess Xiaodian
1994 Fiery Of Lover 烈火情人 He Lin
1995 Rain and Shine 东边日出西边雨 Xiao Nan
1998 Coming and Going 来来往往 Lin Zhu
2000 长缨在手 Gong Yue / Ying'er [24]
2001 Laughing in the Wind 笑傲江湖 Ren Yingying
2002 Black Triangle 黑三角 Xia Yingjie
2002 The Chinese Woman at the Gunpoint of Gestapo 盖世太保枪口下的中国女人 Jin Ling (based on Qian Xiuling)
2003 DA师 Lin Xiaoyan [25]
2003 Half of the Moon 半个月亮 Li Dongna [26]
2006 Close to You and Make Me Warm 靠近你,温暖我 Ding Aiyu [27]
2006 Heroic Legend of the Qing Dynasty 大清风云 Empress Dowager Xiaozhuang [28]
2006 沙家浜 Qingsao [29]
2006 Stone Scissors Cloth 石头、剪刀、布 Aiyu [30]
2006 Bottom Line of Man 男人底线 Shen Congcong [31]
2006 红墨坊 Princess Ziyan [32]
2007 局中局 Jiang Wei [33]
2008 Forgive 宽恕 Zhuang Min [34]
2010 Spy Change 1939 谍变1939 Zhao Yina [35]
2010 Age Mates 同龄人 Tong Nannan [36]
2011 The Beautiful Blooming Flower 美丽鲜花在开放 Ye Guo
2012 皇粮胡同十九号 Feng Xueyan / Feng Ziting [37]
2015 Mother Like Flowers 妈妈像花一样 Zhang Xingfu [38]
2015 Ferocious 来势凶猛 Ma Xiuqin [39]
2019 Doctor of Traditional Chinese Medicine 老中医 Bao Xiu [40]
Novoland: Eagle Flag 九州缥缈录 Bai Lingbo [41]

Àwọn àmì-ẹ̀yẹ tó gbà àti èyí tí wọ́n yàn án fún

àtúnṣe
Ọdún Àmì-ẹ̀yẹ Abala Inú eré tí wọ́n torí rẹ̀ yàn án Àbájáde Ìtọ́kasí.
1992 15th Hundred Flowers Awards Best Actress Ripples Across Stagnant Water Wọ́n pèé
1993 4th Golden Phoenix Awards Society Award Gbàá [42]
2003 20th China TV Golden Eagle Award Best Actress The Chinese Woman at the Gunpoint of Gestapo Wọ́n pèé
2009 1st Macau International Movie Festival Best Supporting Actress The Founding of a Republic Gbàá
2010 30th Hundred Flowers Awards Best Supporting Actress Gbàá
2013 10th Huading Awards Best Actress (Stage) A Dream Like A Dream Gbàá
2015 7th Macau International Movie Festival Best Actress Mr. Six Wọ́n pèé
2016 18th Huading Awards Best Film Actress (Mainland China) Gbàá [43]
7th China Film Director's Guild Awards Best Actress Wọ́n pèé
23rd Beijing College Student Film Festival Best Actress Wọ́n pèé
16th Chinese Film Media Awards Best Supporting Actress Wọ́n pèé
33rd Hundred Flowers Awards Best Actress Gbàá
12th Chinese American Film Festival Best Actress Gbàá [44]
2018 55th Golden Horse Film Festival and Awards Best Supporting Actress Hidden Man Wọ́n pèé [45]
2019 13th Asian Film Awards Best Supporting Actress Wọ́n pèé [46]
2020 7th The Actors of China Award Ceremony Best Actress (Sapphire) Àdàkọ:NA   Iṣẹ́ ń lọ lórí ẹ̀ [47]

Àwọn Ìtọ́kasí

àtúnṣe
  1. "Mtime上许晴的个人档案". Archived from the original on 2017-12-07. Retrieved 2021-08-23. 
  2. Credited as "Summer Qing" in Looper
  3. "Xu Qing Draws Eyes at Jewelry Brand Banquet of VAN Cleef&Arpels". December 17, 2013. Archived from the original on January 8, 2019. Retrieved August 23, 2021. 
  4. "《笑傲江湖》各版任盈盈盘点 许晴最大龄关之琳最美". ifeng (in Edè Ṣáínà). February 21, 2013. 
  5. "《盖世太保枪口下的中国女人》美女许晴出世". Enorth (in Edè Ṣáínà). March 18, 2002. Archived from the original on July 11, 2017. Retrieved August 23, 2021. 
  6. "许晴谈《建国大业》演国母 先辈与孙中山相熟". Mtime (in Edè Ṣáínà). March 9, 2009. Archived from the original on September 16, 2018. Retrieved August 23, 2021. 
  7. "完美演绎"宋庆龄" 许晴澳门斩获最佳女配角奖". Netease (in Edè Ṣáínà). January 4, 2010. 
  8. "低调许晴获高调认可 凭"宋庆龄"一角得奖". Sina (in Edè Ṣáínà). October 18, 2010. 
  9. "Actress Xu Qing signs up with Huayi Bros.". China.org.cn. December 2, 2009. 
  10. "Exclusive Interview: Summer Qing Talks 'Looper', a Tender Bruce Willis, an Oscar-worthy Rian Johnson and More". Desde Hollywood. 
  11. "许晴凭借《如梦之梦》获华鼎奖最佳女话剧演员奖". ifeng (in Edè Ṣáínà). October 8, 2013. 
  12. "老炮儿》曝许晴特辑". Mtime (in Edè Ṣáínà). January 1, 2016. Archived from the original on September 16, 2018. Retrieved August 23, 2021. 
  13. "Winners revealed at Chinese famous film awards". China Radio International. September 25, 2016. Archived from the original on September 26, 2016. Retrieved August 23, 2021. 
  14. "Common, Xu Qing Join Ethan Hawke's '24 Hours to Live'". Variety. May 10, 2016. 
  15. "许晴《导火线》PK范冰冰 两美女进行自我挑战". Mtime (in Edè Ṣáínà). July 12, 2007. Archived from the original on September 16, 2018. Retrieved August 23, 2021. 
  16. "《与妻书》正式杀青 佟大为许晴演绎穿越爱情". Mtime (in Edè Ṣáínà). August 20, 2011. Archived from the original on September 16, 2018. Retrieved August 23, 2021. 
  17. "《恋爱排班表》曝最新海报 许晴甜美床照大胆暗示感情态度". Mtime (in Edè Ṣáínà). May 21, 2015. Archived from the original on September 16, 2018. Retrieved August 23, 2021. 
  18. "奇幻片《封神传奇》曝终极预告". Mtime (in Edè Ṣáínà). June 21, 2016. Archived from the original on August 7, 2020. Retrieved August 23, 2021. 
  19. "徐浩峰新片《刀背藏身》曝国际版海报 许晴春夏主演 "零特效零替身"演员真打实拍". Mtime (in Edè Ṣáínà). February 16, 2017. Archived from the original on September 16, 2018. Retrieved August 23, 2021. 
  20. "姜文《邪不压正》新海报五大主演首度合体". Mtime (in Edè Ṣáínà). June 26, 2018. Archived from the original on June 19, 2019. Retrieved August 23, 2021. 
  21. "李仁港《刺局》剧照&概念图曝光". Mtime (in Edè Ṣáínà). May 14, 2018. Archived from the original on April 20, 2019. Retrieved August 23, 2021. 
  22. "《士为知己者》开机 许晴:这是一部男人戏的电影". People.com (in Edè Ṣáínà). September 15, 2018. 
  23. "《入殓师》导演合作韩庚张国立许晴拍新片". Mtime (in Edè Ṣáínà). August 27, 2018. Archived from the original on January 25, 2019. Retrieved August 23, 2021. 
  24. "众明星"飙戏"《长缨在手》 邵兵许晴大呼过瘾". Sina (in Edè Ṣáínà). March 30, 2001. 
  25. "许晴演军人含泪剪发 《DA师》给央视开好头(图)". Sina (in Edè Ṣáínà). January 4, 2003. 
  26. "陈宝国许晴"各怀鬼胎"联手打造《半个月亮》". Sina (in Edè Ṣáínà). May 29, 2004. 
  27. "《靠近你,温暖我》许晴梅婷柯蓝身陷不伦之恋". Sina (in Edè Ṣáínà). November 14, 2006. 
  28. "《大清风云》许晴版"孝庄"曝光 张丰毅姜文加盟(组图)". Sina (in Edè Ṣáínà). July 20, 2004. 
  29. "许晴、程前、刘金山《沙家浜》5月14日登陆湖北". Sina (in Edè Ṣáínà). May 12, 2006. 
  30. "许晴姜武大玩《石头剪刀布》导演揭秘剧情(图)". Sina (in Edè Ṣáínà). June 26, 2008. 
  31. "濮存昕许晴演绎《男人底线》 八年后再合作(图)". Sina (in Edè Ṣáínà). January 4, 2008. 
  32. "电视剧《红墨坊》热播 许晴女扮男装很自信(图)". Sina (in Edè Ṣáínà). May 10, 2007. 
  33. "许晴《局中局》出演完美白领错综亲情伦理故事". Sina (in Edè Ṣáínà). June 19, 2007. 
  34. "王志文许晴组成美满家庭 《宽恕》再度牵手(图)". Sina (in Edè Ṣáínà). January 5, 2007. 
  35. "《谍变1939》大热荧屏 董勇许晴上演"无间道"". Sina (in Edè Ṣáínà). August 5, 2010. 
  36. "《同龄人》角色年龄大跨度 许晴被称"80后"". Sina (in Edè Ṣáínà). February 10, 2010. 
  37. "《皇粮胡同十九号》开播 许晴挑战新角色(图)". Sina (in Edè Ṣáínà). April 6, 2012. 
  38. "《妈妈像花儿》许晴传递励志剧新理念". Sina (in Edè Ṣáínà). September 25, 2015. 
  39. "抗战剧《来势凶猛》开机 许晴化身女汉子". Sina (in Edè Ṣáínà). April 21, 2014. 
  40. "《老中医》神秘女主曝光 许晴旗袍造型展民国韵致". Sina (in Edè Ṣáínà). September 3, 2017. 
  41. "《九州缥缈录》首发剧照 刘昊然许晴江疏影扮相曝光". ifeng (in Edè Ṣáínà). January 11, 2018. 
  42. "第四届中国电影表演艺术学会奖获奖演员名单" (in Edè Ṣáínà). Archived from the original on 2021-08-23. Retrieved 2021-08-23. 
  43. "第18届华鼎奖澳门颁奖 段奕宏许晴获最佳男女演员奖". People's Daily (in Edè Ṣáínà). April 4, 2016. 
  44. "许晴凭《老炮儿》夺中美电影节最佳女主". Sina (in Edè Ṣáínà). November 4, 2016. 
  45. "金马奖提名公布张艺谋《影》领跑". Mtime (in Edè Ṣáínà). October 1, 2018. Archived from the original on November 6, 2018. Retrieved August 23, 2021. 
  46. "Asian Film Awards: South Korea's 'Burning' Tops Nominations". Hollywood Reporter. November 1, 2019. 
  47. "第七届"中国电视好演员奖"候选名单,易烊千玺马思纯等超百名演员入围". Chongqing Chongbao (in Edè Ṣáínà). September 15, 2020.