Yéyamba Wandzé Mdrou Ndo?
Yéyamba Wandzé Mdrou Ndo? jẹ́ eré aláwàdà kan ti orílẹ̀-èdè Comoros tí wọ́n ṣe ní ọdún 2000, èyí tí adarí rẹ̀ n ṣe Arsin Soiby.[1][2][3] Fíìmù náà ni àkọ́kọ́ fíìmù gígùn ti Comoros.[4]
Yéyamba Wandzé Mdrou Ndo? | |
---|---|
Adarí | Arsin Soiby |
Àwọn òṣèré | Jacqueline Abdillah Abderemane Djimby Djimba Youssouf Msa |
Ìyàwòrán sinimá | Arsin Soiby |
Olùpín | HMZ Productions |
Déètì àgbéjáde | 2000 |
Àkókò | 55 min. |
Orílẹ̀-èdè | Comoros |
Èdè | French |
Àwọn olùkópa
àtúnṣe- Jacqueline Abdillah
- Djimba
- Abderemane Djimby
- Zali Hamadi
- Laher
- Youssouf Msa
- Roukia Saïd
- Arsin Soiby
Àwọn ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ "Yéyamba Wandzé Mdrou Ndo?". filmaffinity. Retrieved 17 October 2020.
- ↑ "Yéyamba Wandzé Mdrou Ndo?: Film de Arsin (2000)". SensCritique. Retrieved 17 October 2020.
- ↑ "Cinema and Video in the Comoros: Yéyamba Wandzé Mdrou Ndo?". comores-online. Retrieved 17 October 2020.
- ↑ "Yéyamba Wandzé Mdrou Ndo? (2000)". moviepilot. Retrieved 17 October 2020.