Yaa Avoe jẹ agbabọọlu lobinrin ilẹ ghana ti a bini ọjọ akọkọ, óṣu July ni ọdun 1982. Agbabọọlu naa ṣere fun awọn ọdọmọbinrin ash town gẹgẹbi defender[1].

Yaa Avoe
Personal information
Ọjọ́ ìbí1 Oṣù Keje 1982 (1982-07-01) (ọmọ ọdún 42)
Playing positionDefender
Senior career*
YearsTeamApps(Gls)
Ash Town Ladies
National team
Ghana women's national football team23(0)
* Senior club appearances and goals counted for the domestic league only.

† Appearances (Goals).

‡ National team caps and goals correct as of 10 September 2007 (before the 2007 FIFA Women's World Cup)

Àṣeyọri

àtúnṣe
  • Avoe kopa ninu Cup FIFA awọn obinrin agbaye ti ọdun 2003 ati 2007[2].

Itọkasi

àtúnṣe
  1. https://fbref.com/en/players/fb35fff8/Yaa-Avoe
  2. https://int.soccerway.com/players/yaa-avoe/19579/