Yahaya Chado Gora je ọkàn lára àwọn olóṣèlú ọmọ orile-ede Naijiria lati ipinle Zamfara . Oje ọkàn lára awon aṣojú sofin ton sójú Maradun/Bakura ni ile asofin àgbà. [1]

  • Idibo Ile-igbimọ Aṣoju Naijiria 2019 ni Ipinle Zamfara

Awọn itọkasi

àtúnṣe