Yam pepper soup
Yam pepper soup jẹ́ oúnjẹ Nàìjíríà tí à ń iṣu puna ṣe. Ó ṣe pàtàkì kí iṣu náà rọ̀.[1][2]
Ọbẹ̀ náà wọ́pọ̀ ni ìhà Gúsù Ìlà-Oòrùn ti Nàìjíríà àti pé díè lára àwọn èròjà ọbẹ̀ yìí ni ehuru, ṣọ̀mbọ̀, oríṣiríṣi ẹran, iyọ̀ àti efinrin.[3][4]
Àwọn èròjà yìí ni ẹ ma fi si nígbà tí iṣu náà bá rọ̀ tí ó sì ti ń di àsáró.[5]
Àwọn oúnjẹ mìíràn
àtúnṣeẸ lè fi Yam pepper soup jẹ ìrẹsì àti dòdò.[6]
Tún wo
àtúnṣe- Igbo Cuisine
- Ogbono soup
- Nigeria cuisine
- Peanut soup
Àwọn Ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ "How To Make Nigerian Yam Pepper Soup". The Guardian Nigeria News - Nigeria and World News (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2022-04-12. Archived from the original on 2022-05-07. Retrieved 2022-06-30.
- ↑ Natural, Sympli (2019-02-16). "Yam and Goat Meat Pepper Soup". Medium (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2022-06-30.
- ↑ omotolani (2018-03-06). "How to cook Nigerian yam pepper soup". Pulse Nigeria (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2022-06-30.
- ↑ a, temitope (2016-09-02). "How to make yam peppersoup". Pulse Nigeria (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2022-06-30.[Ìjápọ̀ tí kò ṣiṣẹ́ mọ́]
- ↑ "Yam pepper soup delight". Daily Trust (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2021-07-18. Retrieved 2022-06-30.
- ↑ "Yam and Goat Meat Pepper Soup". Daily Trust (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2021-03-21. Retrieved 2022-06-30.