Yasmin Saika
Yasmin Saikia jẹ́ Alága Hardt-Nickachos ní Àwọn ẹ̀ka ìkẹ́èkọ́ Àlàáfíà àti olùkọ́ ọ̀jọ̀gbọ́n ti ìtàn-àkọọ́lẹ̀ Gúúsù Àsìá ní Ilé-ẹ̀kọ́ gíga Ìpínlẹ̀ Arizona. Òun ni ònkọ̀wé Àwọn Ìrántí apá kan (Fragmented Memories): Ìjàkadì láti jẹ́ Tai-Ahom ní India (2004) ati Awọn Obirin, Ogun, ati ìṣẹ̀dálẹ̀ Bangladesh: Ṣíṣe Ìrántí 1971 (2011).
' | |
---|---|
Born | Assam, India |
Nationality | American |
Institutions | University of North Carolina-Chapel Hill Arizona State University |
Alma mater | University of Wisconsin-Madison |
Ìbẹ̀rẹ̀ ìgbésí ayé rẹ̀ àti ẹ̀kọ́
àtúnṣeA bí Saikia ní Assam, India.[1][2] Ó parí gboyè ìwá gíga àkọ́kọ́ (Bachelor's degree) àti ìkejì (Master's degree) nínú ìtàn-àkọọ́lẹ̀ ní Ilé-ẹ̀kọ́ gíga Mùsùlùmí Aligarh ní India, lẹ́hìnáà, ó gboyè ìwá gíga ẹ̀ẹ̀kejì (Master's degree) si ní ìtàn-àkọọ́lẹ̀ Gúúsù Asia àti ìwé ẹ̀rí ọ̀jọ̀gbọ́n ní ìtàn-àkọọ́lẹ̀ Gúúsù Asia pẹlú gbígbájúmọ́ ẹ̀kọ́ lori Amẹrika àti Gúúsù ìlà oòrùn Asia ní ilé ẹ̀kọ́ gíga Wisconsin-Madison.[3][4]
Iṣẹ́
àtúnṣeIṣẹ-ṣiṣe akọkọ ti Saikia ṣe ni ìkọ́ni ní ìtàn-àkọọ́lẹ̀ ati ṣíṣe ìwádìí ní ilé ẹ̀kọ́ gíga North Carolina-Chapel Hill. [4]Ó máa ń padà sií Guwahati Nìgbà gbogbo láti ṣà'bẹ̀wò sí ẹbí rẹ̀ àti láti ṣe ìwádìí ní India, ó sì lo ọdún kan ní Pakistan ní ibi tí ó tún ti ṣe ìwádìí.[4] INí ọdún 2001, ó rin ìrìn-àjò lọ sí Bangladesh láti ṣe ìwádìí ó sì bẹ̀rẹ̀ ṣíṣe awọn ìfọ̀rọ̀wánilẹ́nuwò pẹ̀lú àwọn obìnrin, èyi tí ó jẹ́ ìpìlẹ̀ ìwé rẹ; Awọn Obirin, Ogun, ati ìṣẹ̀dálẹ̀ Bangladesh: Ìrántí 1971 ní 2011. [5]
Ní ọdún 2010, ó di Alága Hardt-Nickachos Endowed ní Àwọn ẹ̀ka ìkẹ́èkọ́ Àlàáfíà àti ọ̀jọ̀gbọ́n ìtàn-àkọ́ọ́lẹ̀ ìtàn Gúúsù Àsìá ní Ilé-ẹ̀kọ́ gíga Ìpínlẹ̀ Arizona.[6] Lẹ́hìn tí ó di ọ̀jọ̀gbọ́n ní ASU, ó tẹ̀síwájú láti rin ìrìn-àjò láti ṣe ìwádìí.[7] Ní ọdún 2022, ó tún di Olùdarí ti Ile-iṣẹ (centre) ti Ìrírí àwọn Mùsùlùmí ní Amẹrika ní Ilé-ẹ̀kọ́ gíga ti Ìpínlẹ̀ Arizona.[6][7]
Saikia ti kọ àwọn ìwé púpọ, pẹ̀lú Ni awọn Meadows ti Gold: Telling Tales of the Swargadeos at the Crossroads of Assam (1997), [4] Àwọn ìpìn ìrántí: Ìjàkadì láti jẹ́ Tai-Ahom ní India (2004), ati Awọn Obirin, Ogun, ati ìpìlẹ̀ṣẹ̀ Bangladẹẹṣi. Ó tún tí ṣe àtúnkọ ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn ìwé, pẹ̀lú àwọn àkójọpọ̀ tí ó pinnu láti di iṣẹ́ ẹ̀ta òkò : Àwọn obìnrin àti Àlàáfíà ni Àgbáyé Ìsìláámù: ìjẹ́ akọ tàbi abo, Ipa rẹ̀ àti Abẹ̀wẹ̀ (2015) àti Àlàáfíà àwọn Ènìyàn: Ìrètí fún Ọjọ Ọ̀la àwọn Ènìyàn (2019).[8] Ní ọdún 2022, wọ́n yan-àn gẹ́gẹ́ bí olóòtú fún Mùsùlùmí Gúúsù Asia ìwé oní apá mẹ́ẹ̀dógún láti ilé iṣẹ́ ìròyìn Ilé-ẹ̀kọ́ gíga Cambridge University[9]
Fragmented Memories: Struggling to be Tai‐Ahom in India
àtúnṣeNínú àtúnyẹwò tí Àwọn Ìrántí ìpìn fun Ìwé àtìgbàdégbà ti Àwọn ẹ̀ka ẹ̀kọ́ Asia, Jayeeta Sharma kọ̀wé nípa bí Saikia “ṣe àfihàn fí ojú mìíràn wo Ahom síwájú ìmúnisìn gẹ́gẹ́ bí ìran tí ó ṣi sílẹ̀ tí àwọn ara wọn wá láti oríṣiríṣi àwọn ènìyàn agbègbè náà tí ó kópa nínú ìjọba àwọn jagunjagun kan. Dípò ìdánimọ̀ ti ìrísí, àwọn jagunjagun yìí dé ipò ọlá náà pẹ̀lú ojúrere ọba ní. Lẹ́yìn náà, dídásí àwọn gẹ̀ẹ́sì dásí ọ̀rọ̀ wọn pín wọn níyà nínú ìtumọ̀ Ahom gẹ́gẹ́ bí ẹ̀yà-ìran, wọ́n sì pìlẹ̀ ìdásí ti àbínibí fún ìdánimọ̀ Tai-Ahom."[10] Nínú àtúnyẹwò kan fún Àtúnwò Ìtàn-àkọọ́lẹ̀ Ìlú Amẹ́ríkà, Sanjib Baruah ṣe àpèjúwe ìwé náà gẹ́gẹ́bí “ìṣẹ̀lẹ̀ àtẹ̀jáde pàtàkì” ní ìbámu ti àìní “ìtàn àkọsórí òun àtọwọ́dọ́wọ́ tí ó f'ẹsè múlẹ̀ ní India pẹ̀lú wíwo àwọn ìṣẹ̀lẹ̀ iṣaju agbègbè náà pẹ̀lú àmọ̀dájú”. atipe wón fi òpin sí iye àwọn ìwé ìwọ̀lú fún ìwádìí tí ó wà.[2]
Awọn obinrin, Ogun, ati ìpilẹ̀ṣẹ̀ Bangladesh: Ìrántí 1971
àtúnṣeNínú àtúnyẹwò fún Àwọn ẹ̀tọ́ ọmọ Ènìyàn tí ń wáyé ní ìdámẹ́rin ọdún, Elora Chowdhury àti Devin Atallah ṣapejuwe Àwọn Obìnrin, Ogun, ati Ìpìlẹ̀ṣẹ̀ Bangladesh gẹ́gẹ́bí “àríwòye” nítorí pé ó jẹ́ ọ̀kan nínú àwọn iṣẹ́ ọ̀mọ̀wé díẹ̀ tí wọ́n sọ nípa Ogun Òmìnira Bangladẹẹṣi ní 1971, àti nítorí pé ìwé náà sọ ọ̀rọ̀ lórí ìrírí àwọn òbinrin nígbà ogun[11] Wọ́n tún ṣàpèjúwe ìwé náà gẹ́gẹ́bí “ìtaniláyà nítorí pé ó takò ọ̀pọ̀lọpọ̀ áwọn àhesọ̀ ní orílẹ-èdè náà ti o ti ṣe agbekalẹ ìtanijí orílẹ-èdè Bangladẹẹṣi lẹ́yìn 1971.”[11] Hannah Sholder ṣe àpèjúwe ìwé náà gẹ́gẹ́bí “àrà ọ̀tọ̀” ní àtúnyẹwò fún ìwé àtìgbàdégbà ẹ̀ka ẹ̀kọ́ oríṣi ìmọ̀ nípa Gúúsù Asia kọ ọ́ pé “pẹ̀lú ṣíṣe àfihàn ìrírí àwọn obìnrin Bangladesh láti oríṣiríṣi ẹyà àti àwọn ẹ̀yà, ẹ̀sìn, Saikia ò ta àwọn tí ń fi ojú kan wo ajìjàgbara ogun náà láyà nìkàn, ṣùgbọ́n o tún ṣe àgbéjáde ojú mìíràn tí a lè fi wo ọ̀rọ̀ yìí tí ó sì ṣe àfihàn anfààní láti tún sowọ́pọ̀ wo ọgbẹ́ ogun náà sàn, eyi ti ó ṣe pé ó ṣì wà ára àwọn tí ogun náà ṣojú wọn tàbí àbájáde rẹ̀.”[12]
Àmì ẹ̀yẹ àtí ìdánilọ́lá
àtúnṣe- 2005 Srikanta Datta Best Book Award on Northeast India and the Social Sciences, for Fragmented Memories: Struggling to be Tai-Ahom in India[13]
- 2013 Oral History Association Bienniel Book Award, for Women, War, and the Making of Bangladesh: Remembering 1971[13]
Selected works
àtúnṣe- Saikia, Sayeeda Yasmin (1997). In the Meadows of Gold: Telling Tales of the Swargadeos at the Crossroads of Assam (1. publ ed.). Guwahati: Spectrum Publ. ISBN 9788185319612.
- Saikia, Sayeeda Yasmin (2004). Fragmented Memories: Struggling to be Tai-Ahom in India. Durham, NC: Duke Univ. Press. ISBN 9780822333739.[14]
- Saikia, Yasmin (2011). Women, War, and the Making of Bangladesh: Remembering 1971. Durham (N C.): Duke University Press. ISBN 9780822350385.[15]
- Saikia, Yasmin; Haines, Chad, eds (2015). Women and Peace in the Islamic world: Gender, Agency and Influence. London New York: I.B. Tauris & Co. ISBN 9781784530174.
- Saikia, Yasmin; Haines, Chad, eds (2019). People's Peace: Prospects for a Human Future (First ed.). Syracuse, New York: Syracuse University Press. ISBN 9780815636571.[16]
- Saikia, Yasmin; Rahman, M. Raisur, eds (2019). The Cambridge Companion to Sayyid Ahmad Khan. Cambridge New York, NY Port Melbourne New Delhi Singapore: Cambridge University Press. ISBN 9781108705240.
Personal life
àtúnṣeSaikia is Muslim and a naturalized American citizen.[7]
See also
àtúnṣeReferences
àtúnṣe- ↑ Longhi, Lorraine (13 December 2013). "Connecting with Yasmin Saikia on the study of peace". ASU News (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Arizona State University. Retrieved 3 January 2024.
- ↑ 2.0 2.1 Baruah, Sanjib (2005). "Review of Fragmented Memories: Struggling to be Tai-Ahom in India". The American Historical Review 110 (4): 1150–1151. doi:10.1086/ahr.110.4.1150a. ISSN 0002-8762. JSTOR 10.1086/ahr.110.4.1150a. https://www.jstor.org/stable/10.1086/ahr.110.4.1150a.
- ↑ "Yasmin Saikia". search.asu.edu (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Arizona State University. Retrieved 3 January 2024.
- ↑ 4.0 4.1 4.2 Boruah, Maitreyee (28 October 2004). "A historian who digs the past for a better future" (in en). The Telegraph (India). https://www.telegraphindia.com/north-east/a-historian-who-digs-the-past-for-a-better-future/cid/1551239.
- ↑ Kumar, Meenakshi (5 February 2012). "Suffering beyond a war" (in en-IN). The Hindu. https://www.thehindu.com/books/suffering-beyond-a-war/article2856807.ece.
- ↑ Fan, Sherry (September 23, 2022). "ASU's Center of Muslim Experience in the US opens". The State Press. https://www.statepress.com/article/2022/09/asu-center-of-muslim-experience-opens.
- ↑ 7.0 7.1 "New ASU center aims to showcase Muslim contributions, accomplishments in US". ASU News (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Arizona State University. 29 August 2022. Retrieved 3 January 2024.
- ↑ "Peace Studies: Chair | Center for the Study of Religion and Conflict". csrc.asu.edu. Arizona State University. Archived from the original on 3 January 2024. Retrieved 3 January 2024.
- ↑ Beeson, Dawn R. (18 July 2022). "ASU South Asia expert poised to make global impact in new role". ASU News (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Arizona State University. Retrieved 3 January 2024.
- ↑ Sharma, Jayeeta (2007). "Review of Fragmented Memories: Struggling to Be Tai-Ahom in India". The Journal of Asian Studies 66 (1): 277–279. doi:10.1017/S0021911807000484. ISSN 0021-9118. JSTOR 20203149. https://www.jstor.org/stable/20203149.
- ↑ 11.0 11.1 Chowdhury, Elora Halim; Atallah-Gutierrez, Devin G. (2012). "Review of Debunking "Truths," Claiming Justice: Reflections on Yasmin Saikia, "Women, War, and the Making of Bangladesh: Remembering 1971"". Human Rights Quarterly 34 (4): 1201–1211. doi:10.1353/hrq.2012.0070. ISSN 0275-0392. https://www.researchgate.net/publication/260103904. Retrieved 3 January 2024.
- ↑ Sholder, Hannah (15 May 2012). "Yasmin Saikia, Women, War, and the Making of Bangladesh: Remembering 1971" (in En). South Asia Multidisciplinary Academic Journal. doi:10.4000/samaj.3393. ISSN 1960-6060. https://journals.openedition.org/samaj/3393. Retrieved 3 January 2024.
- ↑ 13.0 13.1 "People's Peace – Syracuse University Press". press.syr.edu. Syracuse University Press. Retrieved 3 January 2024.
- ↑ Additional reviews of Fragmented Memories
- Aggarwal, Ravina (2006). "Review of Fragmented Memories: Struggling to Be Tai-Ahom in India". American Anthropologist 108 (2): 434–435. doi:10.1525/aa.2006.108.2.434. ISSN 0002-7294. JSTOR 3804842. https://www.jstor.org/stable/3804842.
- Fisher, Michael H. (2006). "Review of Fragmented Memories: Struggling to Be Tai-Ahom in India". The Journal of Interdisciplinary History 37 (2): 337–338. doi:10.1162/jinh.2006.37.2.337. ISSN 0022-1953. JSTOR 4139601. https://www.jstor.org/stable/4139601.
- ↑ Additional reviews of Women, War, and the Making of Bangladesh
- Ahsan, Syed Badrul (4 February 2012). "Dhaka's Despair" (in en). The Indian Express. https://indianexpress.com/article/news-archive/web/dhaka-s-despair/.
- Zutshi, Chitralekha (September 2012). "Yasmin Saikia. Women, War, and the Making of Bangladesh: Remembering 1971.". H-Net Reviews. https://www.h-net.org/reviews/showpdf.php?id=34711. Retrieved 3 January 2024.
- Nair, Neeti (2013). "Review of Women, War, and the Making of Bangladesh: Remembering 1971". The American Historical Review 118 (1): 169–170. doi:10.1093/ahr/118.1.169. ISSN 0002-8762. JSTOR 23425491. https://www.jstor.org/stable/23425491.
- Jahan, Rounaq (2014). "Review of Women, War, and the Making of Bangladesh: Remembering 1971". The Journal of Asian Studies 73 (3): 842–844. doi:10.1017/S0021911814000928. ISSN 0021-9118. JSTOR 43553385. https://www.jstor.org/stable/43553385.
- Kilinçoğlu, Sevil Çakir (2015). "Review of Women, War, and the Making of Bangladesh: Remembering 1971". The Oral History Review 42 (1): 164–166. doi:10.1093/ohr/ohv031. ISSN 0094-0798. JSTOR 43863639. https://www.jstor.org/stable/43863639.
- ↑ Review of People's Peace
- Rinker, Jeremy A. (October 2020). "People's Peace: Prospects for a Human Future." (in en). Peace & Change 45 (4): 609–612. doi:10.1111/pech.12437. ISSN 0149-0508. https://doi.org/10.1111/pech.12437.