Yejide Kilanko (tí a bí ní ọdún 1975) jẹ́ ọ̀ǹkọ̀wé ìwé Ìtàn_Àrọ̀sọ àti Ọ̀ṣìṣẹ́ Àwùjọ ti Orílẹ̀_Èdè Nàìjíríà àti Orílẹ̀ èdè Canada. Ó jé gbajúmọ̀ fún sísọ ìwà-ipá sí àwọn obìnrin nínú iṣẹ́ rẹ̀. Ìtàn Àkọ́kọ́ tí ó tẹ̀ jáde, Àwọn Ọmọbìnrin tí ó Rin Ọnà yìí, Ìtàn Àrọ̀sọ orílẹ̀ èdè Canada jẹ́ Olutàjà tí ó dára jù lọ ní ọdún 2012.

Ìgbésí ayé ìbẹ̀rẹ̀ àti ẹ̀kọ́ àtúnṣe

A bí Kilanko ní ọdún 1975 ní Ìlú Ìbàdàn Nàìjíríà, ní ibi tí bàbá rẹ̀ tí ń ṣiṣẹ́ gẹ́gẹ́bí olùkọ́ ilé-ẹ̀kọ́ gíga. Ó bẹ̀rẹ̀ Ẹ̀wì kíkọ láti kékeré. Ó kẹ́kọ̀ọ́ sáyẹ́ǹsì ìṣèlú ní fásitì ti Ìbàdàn .

Gbé lọ sí Ìlú Kánádà àti iṣẹ́ àwùjọ àtúnṣe

Ní ọdún 2000, Kilanko kúrò ní Nàìjíríà, ó fẹ́ ọmọ Amẹ́ríkà kan ó sì kó lọ sí Laurel, Maryland, ní Amẹ́ríkà. Ní Ọdún 2004, ó kó lọ sí Orílẹ̀ èdè Kánádà, ní ibi tí ó ń gbé ní Chatham_Kent, Ontario.

Maryland, ni AmẹrikaÓ tún kó lọ sí u Kana ,í ọdún 2004,ní ibi tó ń gbé báyìínií i Chatham-Kent, Ontario .

Ní Ìlú Kánádà, ó kọ́ ẹ̀kọ́ nípa Iṣẹ́ Àwùjọ ní University of Victoria ati University of Windsor . Ó ṣíṣe gẹ́gẹ́ bí Oníwòsàn ní Ìlera Ọpọlọ àwọn ọmọdé .

Kilanko kọ́kọ́ gbá ojú mọ́ Ewì, ìgbà tí ó yá ó yí padà sí ìtàn àròsọ̀. Ó pinnu láti kọ ìwé ìtàn àkọ́kọ́ lẹ́yìn ìpènijà pẹ̀lú hílàhílo tí ó gbọ́ nípa ìrírí àwọn ọmọdé tí ó bá ṣíṣe pọ̀ gẹ́gẹ́ bí Olùgbani_nímọ̀ràn nípa ìlera ọpọlọ. pinnu láti kọkọ́kọ́ lẹ́yìn ìpènijà pẹ̀lú hílàhílo tí ó gbọ́ nípa ìrírí àwọn ọmọdé tí ó bá ṣíṣe pọ̀ gẹ́gẹ́ bí Olùgbani_nímọ̀ràn tàn àkókòÓO . O ti ṣetan lati kọ iwe aramada akọkọ rẹ lẹhin ti o tiraka pẹlu ibalokanjẹ aṣebiakọ lati gbọ nipa awọn iriri ti awọn ọmọde ti o ṣiṣẹ pẹlu bi oludamọran ilera ọpọlọ.

Ìwé àkọ́kọ́ rẹ̀ , Àwọn Ọmọbìnrin tí ó Rin Ọnà yìí (Daughters Who Walk This Path) tí a tẹ̀ jáde ní ọdún 2012. Ṣètò ní ìlú abínibí rẹ̀ , Ìbàdàn , ó dá lórí ìfípábanilòpọ̀ àti ìwà_ilá si àwọn obìnrin àti àwọn ọmọdé ní Nàìjíríà , a sọ ọ́ nípasẹ̀ ojú ọmọdé tó ń sọ ìtàn. Àwọn tó ń ṣe Àgbéyẹ̀wọ̀ ṣe àpèjúwe rẹ̀ gẹ́gẹ́ bí fífọ́ ààlà lórí èèwọ̀ ti ìjíròrò ìfípábanilòpọ̀, pàápàá jù lọ lórí orílẹ̀ èdè Nàìjíríà. .

Àwọn Ọmọbìnrin tí ó Rin Ọnà yìí (Daughters Who Walk This Path) jẹ́ Canada National Fiction ìwé tí ó tà jù lọ fún ọ̀pọ̀lọpọ̀ ọsẹ̀. Wọ́n gbe jáde lórí àtòjọ Globe and Mail ti Ọgọ́rùn-ún (100)ìwé tí ó dára jù lọ ní ọdún 2012. Ní Ọdún 2014 ọ̀ǹkọ̀wé ọmọ orílẹ̀ èdè Nàìjíríà Chimamanda Ngozi Adichie dámọ̀ràn ìwé náà fún ìwé tí wọ́n ń kà nígbà Ẹ̀ẹ̀rù (Summer Reading) nínú The Guardian. . .

Wọ́n yan ìwé ìtàn náà fún Nigeria Prize for Literature ní 2016, lẹ́yìn tí àtẹ̀wẹ́ ọmọ Nigeria kan gbe jáde ní bẹ̀. Ẹ̀bùn náà lọ sí ọwọ́Abubakar Adam Ibraheem fún ìwé rẹ̀ Season of Crimson Blossom.

o ni ọdun 2016́hìn tí àtẹ̀wẹ́ Nàìjíríà kan gbe jáde ní bẹ̀.kan. [1] Ẹ̀bùn náà lọ sí ọwọ́Abubakar Adam Ibrahim fún ìwé rẹ̀ Season of Crimson Blossoms .

[2]Iṣẹ́ lemọ́_lemọ́ rẹ̀ lórí Ìtàn_Àrọ̀sọ, The novella Chasing Butterflies, ni a tẹ̀ jáde ní 2015 gẹ́gẹ́ bíi Àjọ tó ń kó owó jọ fún Wordreader . [3] [4] Ó tún jíròrò lórí ìwà-ipá sí àwọn obìnrin, Ṣíṣe àfojúsùn lórí ìwà

oá abẹ́léa-ipa ile.

Ní ọdun 2018, ó ṣe àtẹ́jáde ìwé àwọn ọmọdé kan, Erin wà nínú Aṣọ Mí (There ìs án Elephant ín My Wardrobe) , èyí tí ó pinnu láti ṣe ìrànwọ́lọ́ fún àwọn ọmọdé pẹlu aibalẹ. [3] [5]

Látàrí ìwé ìtàn Ìwé àfọwọ́kọ rẹ̀(her Manuscript) "èyí tí ó jẹ́ ìtàn tòótọ́ tí ó tún ṣe àfikún nípa àwọn ọmọbinrin nọ́ọ́sì ọmọ Nàìjíríà tó ń gbé ní Amẹ́ríkà tí àwọn ọkọ tí ó jù wọn lọ ṣekúpa " jẹ́ ìwé tí wọ́n kó sínú àkọsílẹ̀ fún Ẹ̀bùn Guernica ti ìlú Kánádà fún Literary Fiction ni Ọdún 2019 lábẹ́ àkọlé ìṣẹ́ Moldable Women. Wọ́n tẹ̀ jáde ní ọdún 2021 gẹ́gẹ́ bíi Orúkọ Rere(Good Name) .


Kilanko pe ara rẹ̀ ní Alátìlẹyìn ìn tó ń jà fẹ́tọ̀ọ́ obìnrin àti ṣíṣe àpèjúwe iṣẹ́ rẹ̀ gẹ́gẹ́ bíi àtìlẹyìn fẹ́tọ̀ọ́ ọmọbìnrin. Ó ní àwọn Òǹkọ̀wé Obìnrin tí ilẹ̀ Áfíríkà àti ti ilẹ̀ Áfíríkà Amẹ́ríkà bíi Buchi Emecheta, Chika Unigwe, Toni Morrison àti Alice Walker ni Ipa púpọ̀ lórí òun gidigidi.



[4]


Àwọn Ìtọ́kasí àtúnṣe

  1. "11 Authors Shortlisted for the Nigerian Prize for Literature 2016". 2016-07-17. https://allafrica.com/stories/201607170238.html. 
  2. Àṣìṣe ìtọ́kasí: Invalid <ref> tag; no text was provided for refs named :0
  3. 3.0 3.1 "Yejide Kilanko signs contract for new book". 2019-10-26.  Àṣìṣe ìtọ́kasí: Invalid <ref> tag; name ":5" defined multiple times with different content
  4. 4.0 4.1 Ibrahim, Abubakar Adam (2016-01-30). "'Being a Writer Is a Huge Part of My Identity'". https://allafrica.com/stories/201601310040.html. 
  5. "Author tackles issue of child anxiety; Guest book reading part of Black History Month programming". Chatham Daily News. 2010-02-25.