Yetunde Odunuga (ti a bi ni ọjọ kankandinlogun osu Kọkànlá ọdun 1997) je afẹṣẹja orilẹede Naijiria ti o gba ami ẹyẹ idẹ kan ni ere Agbaye 2018 .

Iṣẹ-ṣiṣe àtúnṣe

Yetunde dije ni 2018 Commonwealth Games. O gba ami idẹ ninu ìdíje middleweight pelu Caroline Veyre.

Ni ọdun 2017, Yetunde Odunuga, ti o je Omo ologun ti Nigerian Army, gba ami Goolu ni ìdíje ti awon obinrin ni ipele women’s lightweight ninu ere ije African Amateur Boxing Championships, Brazzaville, Congo.

Awọn itọkasi àtúnṣe

Ita ìjápọ àtúnṣe