Adeyinka Faleti (tí wọ́n bí ní June 20, 1976)[2] jẹ́ ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà tó tan mọ́ ìlú America, tó jẹ́ olúṣèlú àti ológun fún ìlú America. Ó gboyè Bachelor of Science láti United States Military Academy ní West Point àti Juris Doctor láti Washington University in St. Louis.[3][4][5]

Yinka Faleti
Ọjọ́ìbíAdeyinka Faleti[1]
Oṣù Kẹfà 20, 1976 (1976-06-20) (ọmọ ọdún 47)
Lagos, Nigeria
Ẹ̀kọ́United States Military Academy (BS)
Washington University School of Law (JD)
Political partyDemocratic
Olólùfẹ́Ronke Faleti
Àwọn ọmọ4
WebsiteCampaign website
Military career
Allegiance United States
Service/branchÀdàkọ:Country data United States Army
Years of service1998–2004
Rank Captain
Battles/warsOperation Desert Spring
Operation Enduring Freedom

Àọn ìtọ́kasí àtúnṣe

  1. Balogun, Yahaya (January 27, 2020). "As Yinka Faleti explores American expcetionalism, let's support him". Nigeriaworld. Retrieved May 29, 2021. 
  2. "Yinka Faleti For Missouri". www.facebook.com (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2020-07-06. 
  3. Àṣìṣe ìtọ́kasí: Invalid <ref> tag; no text was provided for refs named :6
  4. Àṣìṣe ìtọ́kasí: Invalid <ref> tag; no text was provided for refs named :1
  5. King, Chris (April 11, 2020). "Yinka Faleti is only Democrat to file to run against Ashcroft for secretary of state". St. Louis American (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2020-07-06.