Yohanis Algaw ni a bini ọjọ kẹrinla, óṣu August ni ọdun 1999 jẹ ẹ̀ni to ma n sarè fun ilẹ Ethiopia[1][2][3][4][5].

Yohanis Algaw
Òrọ̀ ẹni
Orúkọ àbísọWale Yohanis Algaw
Ọmọorílẹ̀-èdèEthopian
Ọjọ́ìbí14 Oṣù Kẹjọ 1999 (1999-08-14) (ọmọ ọdún 25)
Height180cm
Weight70kg
Sport
Orílẹ̀-èdèEthopia
Erẹ́ìdárayáAthletics
Event(s)200 m

Igbèsi Aye Arakunrin naa

àtúnṣe

Yohanis ti a bi si ilẹ Ethiopia kopa ninu óriṣiriṣi idije ilẹ̀ afirica Ninu wọn ni idije CAA senior ti ilẹ afirica ni ọdun 2022[6][7].

Aṣèyọri

àtúnṣe
Ọdun Idijè Ipó Ayẹyẹ Asiko Wind (m/s) Venue Notes
Ọdun 2016 World U20 Championships Ipo kẹrin 10,000 Metres Race Walk 40:55:96 Zdzislaw Krzyszkowiak Stadium, Bydgoszcz, Poland
Ọdun 2017 African U20 Championships Ipo Akọkọ 10,000 Metres Race Walk 44:43:47 Tlemcen Algeria
Ọsun2018 National Championships Ipo Akọkọ 20 Kilometres Race Walk 1:26:16 Addis Abeba Ethopia
Ọdun 2019 National Championships Ipo Akọkọ 10,000 Metres Race Walk 42:41:6h Addis Abeba Ethopia
Ọdun 2019 All African Games Ipo kèji 20 Kilometres Race Walk 1:22:50 Prince Moulay Abdellah Stadium, Rabat, Morocco

[8] [9]

Ọdun 2022 African Championships Ipó kẹta 20 Kilometres Race Walk 1:22:21 Côte d'Or National Sports Complex, St Pierre, Mauritius

Àwọn Ìtọ́kasí

àtúnṣe
  1. https://worldathletics.org/athletes/ethiopia/yohanis-algaw-14714605
  2. "Ẹda pamosi". Archived from the original on 2022-09-25. Retrieved 2023-03-08. 
  3. https://worldathletics.org/athletes/ethiopia/yohanis-algaw-14714605
  4. https://media.aws.iaaf.org/competitiondocuments/pdf/7138851/AT-20KR-M-f----.SL2.pdf
  5. https://www.caachamps2016.co.za/Home/AthleteList?country=18&Name=Ethiopia
  6. "Ẹda pamosi". Archived from the original on 2023-03-08. Retrieved 2023-03-08. 
  7. https://www.the-star.co.ke/sports/athletics/2022-06-13-ngii-credits-hilly-training-terrain-for-race-walk-gold-in-mauritius/
  8. "African Games (Athletics) Athlete Profile : WALE Yohanis Algaw". web.archive.org. September 28, 2019. Archived from the original on September 28, 2019. Retrieved March 8, 2023. 
  9. "Kenya bags two more golds at African Games". Nation. July 4, 2020.