Yola

Olú-ìlú ìpínlè Adamawa, Nàìjíríà

Yola di olú-ìlú àti ìlú tí ó tóbi jù ní f Ìpínlẹ̀ Adamawa, Nàìjíríà. Ìlú náà wà ní olùgbé 336,648 ní ọdun 2010.[1] Yola pín sí méjì, àwọn ni ìlú Yola àtijó níbi tí Lamido ìlú náà gbé àti ìlú Jimeta, ìlú Jimeta ní àárín ètò ọ̀rọ̀ ajé Yola.

Location of Yola in Nigeria


9°14′N 12°28′E / 9.23°N 12.46°E / 9.23; 12.46

Àwọn Ìtókasí

àtúnṣe
  1. "Yola | Hometown.ng™" (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2018-03-31. Retrieved 2021-06-25.