Yolanda George-David tí àwọn ènìyàn mọ̀ sí Aunt Landa jẹ́ Dókítá ọmọ Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà. Ó jẹ́ Dókítà tó ní ìmọ̀ púpò nípa iṣẹ́ abẹ ọpọlọ.[1][2][3]

Yolanda George-David
Ọjọ́ìbíYolanda George
Ìlú New York, orílẹ̀ èdè Amerika
Orílẹ̀-èdèỌmọ Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà mọ́ Amẹ́ríkà
Iléẹ̀kọ́ gíga
Iṣẹ́Medical Doctor, Radio Host, Humanitarian and Human Right ativist
Ìgbà iṣẹ́2005–present

Ìpìlẹ̀ àti Ẹ̀kọ́ rẹ̀

àtúnṣe

Yolanda bẹ̀rẹ̀ sí ń ṣisẹ́ láti ran àwọn ènìyàn lọ́wọ́ nígbà tí ó jẹ́ ọmọ ọdún mẹ́rìndínlógún.[4] Ó kàwé gboyè ní Yunifásitì ti Pittsburgh, Pittsburgh kí ó tẹ ẹ̀kọ́ rẹ̀ síwájú ní Harvard Medical School níbi tí wọ́n ti kọ nípa ìmò isẹ́ abẹ ọpọlọ.

Àwọn Ìtọ́kasí

àtúnṣe
  1. "DR. YOLANDA GEORGE-DAVID, MEDICAL DOCTOR, HUMANITARIAN AND MEDIA PERSONALITY, TO SPEAK AT PRIDE WOMEN CONFERENCE 2018". Pride Magazine Nigeria (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2018-04-21. Retrieved 2020-11-22. 
  2. Woman, Urban (2018-12-22). "Join Dr Yolanda N. George-David & Alibaba at Aunt Landa's Market Square tagged "Intervention Edition" Today, 22nd December, 2018". Urban Woman Magazine (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2020-11-22. 
  3. "Dr Yoland George aka Aunty Landa, is Vlisco New Brand Ambassador". Tribe and Elan (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2018-03-27. Archived from the original on 2020-11-29. Retrieved 2020-11-22. 
  4. Nigeria, Blossom. "Dr Yolanda George-David Also Known As 'Aunt Landa' Gets Commendation On Humanitarian Efforts From Vlisco | Blossom Nigeria" (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2020-11-22. [Ìjápọ̀ tí kò ṣiṣẹ́ mọ́]