Yorùbá fún Sáyẹ́nsì àti Ìṣírò
(Àtúnjúwe láti Yoruba fun Sayensi ati Isiro)
- Slope = Ìtẹ̀
- Length = Ìbú
- Volume = Ìkúnsi
- Mass = Ọ̀pọ̀
- Time = Àsìkò
- Distance = Jíjìnàsí
- Abstract = Àfòyemọ̀
- Rate = Ratio = Ìpín
- Degree = Ìyí
- Breadth = Iro
- Fraction = Ìdá
- Number = Nọ́mbà
- Triangle = Anígunmẹ́ta
- Motion = Ìgbéra
- Element = Àpilẹ̀sẹ̀
- Diameter = Ìlàrin
- Weight = Ìwúwo
- Electricity = Ìtanná
- Electronics = Ẹ̀rọ oníná
- Electron = Atanná
- Electric current = Ìwọ́ iná
- Field = Pápá
- Electromagnetism = Inágbéringbérin
- Magnetic field = Pápá gbéringbérin
- Solution = Ojútùú
- Solve = S'ojútùú
- Equation = Ìdọ́gba
- Equal = Dọ́gba
- Quantity = Ọ̀pọ̀iye
- Quality = Àwúlò
- Property = Àdámọ̀
- Area = Agbègbè
- Calculus = Ìsirò kálkúlọ́sì
- Trigonometry = Ìwọ̀n anígunmẹ́ta
- Sphere = Roboto
- Coordinate = Ipòìdojúkọ
- Surface = Òdeojú
- Plane = Pẹpẹ
- Science = Sáyẹ́nsì
- Average = Àriniye
- Decimal = Nọ́mbàmẹ́wàá
- Point = Ojúàmì
- Heat = Ooru
- Temperature = Ìgbónásí
- Planet = Plánẹ́tì
- Universe = Àgbàlá-ayé
- Earth = Ilẹ̀-ayé
- Solar = Tòòrùn
- Energy = Okun
- Work = Isẹ́
- Polygon - Anígunpúpọ̀
- Physical science = Sáyẹ́nsì àfojúrí
- Physics = Ìmọ̀ aláfojúrí
- Acid = Omi-olóró
- Verb = Ase-ọ̀rọ̀
- Adverb = Alátise-ọ̀rọ̀
- Sky = òfuurufú
- Space = ààyè
- Alcohol = Otí
- Alphabet = Títò Lẹ́tà
- Algebra = Áljẹ́brà
- Amenities = Amáyédẹ̀rọ̀
- Anglican = Ìjọ àgùdà
- Ape = Akítì
- Velocity =
- Speed =
- Cube =
- Particle =
- Radius =
- Density =
- Matter =
- Solid =
- Acceleration =