Yoshihiko Noda
Olóṣèlú Ọmọ Orílẹ̀-èdè Japan
Yoshihiko Noda (野田 佳彦 Noda Yoshihiko , born 20 May 1957) je oloselu ara Japan ti Egbe Demokratiki ile Japan (DPJ), omo egbe Ile awon Asoju ninu Diet (ile asofin). Lati 2 September 2011 o di Alakoso Agba ile Japan leyin ti Akihito Oba ile Japan yansipo.
Alakoso Agba ile Japan | |
---|---|
Lọ́wọ́lọ́wọ́ | |
Ó gun orí àga 2 September 2011 | |
Monarch | Akihito |
Asíwájú | Naoto Kan |
Alakoso fun Inawo | |
In office 8 June 2010 – 2 September 2011 | |
Alákóso Àgbà | Naoto Kan |
Asíwájú | Naoto Kan |
Arọ́pò | Jun Azumi |
Igbakeji Agba Alakoso fun Inawo | |
In office 16 September 2009 – 8 June 2010 Served alongside: Naoki Minezaki | |
Alákóso Àgbà | Yukio Hatoyama |
Asíwájú | Wataru Takeshita Masatoshi Ishida |
Arọ́pò | Motohisa Ikeda Naoki Minezaki |
Àwọn àlàyé onítòhún | |
Ọjọ́ìbí | 20 Oṣù Kàrún 1957 Funabashi, Japan |
Ẹgbẹ́ olóṣèlú | Democratic Party (1998–present) |
Other political affiliations | Japan New Party (1992–1994) |
Alma mater | Waseda University |
Website | Official website |
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |