Yoshio Nishina
Yoshio Nishina (仁科 芳雄 Nishina Yoshio , December 6, 1890 – January 10, 1951) lo je baba apilese iwadi fisiksi odeoni ni Japan. O se ajoda afida Klein–Nishina. O je oluwadi akoko RIKEN be sini o je oluko opo awon onimo fisiksi ti ninu won je awon Elebun Nobel meji: Hideki Yukawa ati Sin-Itiro Tomonaga. Nigba Ogun Agbaye 2k o je olori eto atomu Japan. Koto Nishina ni oju osupo gba oruko re.
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |