Yoweri Kaguta Museveni (Yoweri Museveni.ogg pronunciation ) (ojoibi 1944)[1] ti fìgbà kan jẹ́ Olórí Ológun ati Ààrẹ orílẹ̀-èdè Uganda láti ọjọ́ kẹrìndínlọ́gbọ̀n oṣù kìíní ọdún (26th January 1986).

Yoweri Kaguta Museveni
President of Uganda
Lọ́wọ́lọ́wọ́
Ó gun orí àga
26 January 1986
Alákóso ÀgbàSamson Kisekka
George Cosmas Adyebo
Kintu Musoke
Apolo Nsibambi
Vice PresidentSamson Kisekka
Specioza Kazibwe
Gilbert Bukenya
AsíwájúTito Okello
Àwọn àlàyé onítòhún
Ọjọ́ìbíc. 1944 (ọmọ ọdún 79–80)
Ntungamo, Uganda Protectorate
Ẹgbẹ́ olóṣèlúNRM
(Àwọn) olólùfẹ́Janet Museveni



Àwọn Ìtọ́kasí

àtúnṣe
  1. Sources are divided on Museveni's exact year and place of birth. While the year of 1944 is the most prominent in discourse on Museveni (Encyclopædia Britannica, Encyclopedia.com Archived 2004-04-27 at the Wayback Machine., Encarta Archived 2005-03-27 at the Wayback Machine. and Columbia Encyclopedia), 1945 or 1946 have also been suggested as possible years of birth (Oloka-Onyango 2003 Project MUSE).