Yunifásítì Howard
Yunifásítì Howard (ní èdè Gẹ̀ẹ́sì: Howard University tàbí Howard tàbí HU) ni yunifásítì aládáni, tó ní ìwé áṣẹ látọwọ́ ìjọba àpapọ̀ tó bùdó sí Washington, D.C. ní Amẹ́ríkà. Yunifásítì Howard jẹ́ ìkan nínú àwọn yunifásítì tí wọ́n dásílẹ̀ fún àwọn aláwọ̀dúdú (HBCU) ní Orílẹ̀-èdè Amẹ́ríkà. Wọ́n dá Yunifásítì Howard sílẹ̀ ní 1867.
Howard University | |
---|---|
[[File:|frameless|alt=]] | |
Motto | Veritas et Utilitas |
Motto in English | "Truth and Service" |
Established | Oṣù Kẹta 2, 1867 |
Type | Private, HBCU |
Endowment | $692.8 million (2019)[1] |
President | Wayne A. I. Frederick |
Provost | Anthony Wutoh[2] |
Students | 9,399 (Fall 2019)[3] |
Undergraduates | 6,526 (Fall 2019)[3] |
Postgraduates | 2,873 Fall 2019)[3] |
Location | Washington, D.C., United States |
Campus | Urban; 300 acres (1.2 km2) |
Former names | Howard Normal and Theological School for the Education of Teachers and Preachers |
Newspaper | The Hilltop |
Colors | Blue, White, and Red[4] |
Website | howard.edu |
Howard University logo.svg |
Ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ As of June 30, 2019. "U.S. and Canadian 2019 NTSE Participating Institutions Listed by Fiscal Year 2019 Endowment Market Value, and Percentage Change in Market Value from FY18 to FY19 (Revised)". National Association of College and University Business Officers and TIAA. Retrieved April 19, 2020.
- ↑ "HU's Provost Anthony Wutoh".
- ↑ 3.0 3.1 3.2 "Fall 2014-Fall 2019 Students Enrollment Trends". Howard University.
- ↑ Howard University Identity Guidelines. May 22, 2015. https://www.howard.edu/secretary/documents/HU_IDENTITY2016.pdf. Retrieved July 22, 2016.