Yunifásítì Tẹknọ́lọ́jì Àpapọ̀ ilú Àkúrẹ́

Yunifásítì Tẹknọ́lọ́jì Àpapọ̀ ilú Àkúrẹ́ ni yunifásítì ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà. Ni óṣu April, ọdun 2023, Ọgbẹni Charles Adẹlẹyẹ to jẹ ọmọ ọdun mẹrin din lọgọta ni a fi jẹ registrar tuntun fun ilè iwè giga naa ti Ọgbẹni Robert Awoyẹmi to jẹ ọmọ ọdun mẹta leelaadọta jẹ alakoso yara ikawe tuntun ta ṣẹṣẹ yan[1].

Federal University of Technology, Akure
MottoTechnology for Self Reliance
Established1981
TypePublic
ChancellorAlhaji Isa Mustafa Agwai I, the Emir of Lafia and the chairman of Nasarawa State Council of Chiefs
Vice-ChancellorProf. Adebisi Balogun
Admin. staffna
Students10,000 Approx
Undergraduates8,000 Approx
Postgraduates2,000 Approx
LocationAkure, Ondo State, Nigeria
CampusObanla and Obakekere + Expanse of land on Owo-Benin Road
ColorsPurple     
Websitewww.futa.edu.ng