Yunifásitì Adekunle Ajasin
Yunifásítì ti gbogbogbo ni Naijiria
Yunifásitì Adekunle Ajasin, Akungba-Akoko (AAUA) jẹ́ ọ̀kan lára àwọn Yunifásitì ìjọba ìpínlè Ondo.[1] Yunifásitì náà wà ní Akungba Akoko, Ìpínlẹ̀ Òndó, Nàìjíríà.
Yunifásitì Adekunle Ajasin | |
---|---|
Adekunle Ajasin University Akugba Akoko main gate.jpg | |
Motto | For Learning and Service |
Established | December 1999 |
Type | Public |
Vice-Chancellor | Olugbenga E. Ige |
Students | over 20,000 |
Location | Akungba-Akoko, Ìpínlẹ̀ Ondo, Nàìjíríà 7°28′45″N 5°44′54″E / 7.479234°N 5.748411°ECoordinates: 7°28′45″N 5°44′54″E / 7.479234°N 5.748411°E |
Website | aaua.edu.ng/ |
Ìtàn
àtúnṣeÌjọba ìpínlè Ondo kókó dá Yunifásitì Adekunle Ajasin kalè gẹ́gẹ́ bi Yunifásítì Obafemi Awolowo ní ọdún 1982, adarí Yunifásitì náà nígbà yẹn ni Olóyè Michael Adekunle Ajasin.[2] Ìjọba ológun tí ó tẹ́le yí orúkọ Yunifásitì náà dà sí Yunifásitì ìpínlè Ondo ní ọdun 1985.
Àwọn Ìtókasí
àtúnṣe- ↑ "Adekunle Ajasin University Akungba | www.aaua.edu.ng". www.myschoolgist.com.ng. Retrieved 2016-03-23.
- ↑ "Adekunle Ajasin University – …21st Century University, properly called!" (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Archived from the original on 2020-05-11. Retrieved 2020-05-28.