Moegamat Yusuf Maart (ti a bi ni ọjọ ketadinlogun oṣu Keje odun 1995) jẹ agbabọọlu South Africa ti o n gba iwaju fun ẹgbẹ South Africa Premier Division Sekhukhune United ati ẹgbẹ orilẹ-ede South Africa .

Ise Egbẹ Agbabọọlu

àtúnṣe

Orlando Pirates

àtúnṣe

Maart ni a bi ni Cape Town, o si dagba ni Atlantis . Orlando Pirates ṣe akiyesi rẹ ni ọdun 2016 lẹhin ti won yan Gẹgẹ bi eniti o dara julo ninu idije SAB U-21 ti ọdun yẹn. [1] O kọkọ darapọ mọ ẹgbẹ ifiṣura ẹgbẹ, ṣugbọn o gba ifẹsẹwọnsẹ akọkọ rẹ ni ọjọ 12 Oṣu Kẹta ọdun 2017 bi aropo ninu iṣẹgun 3–1 wọn lori EC Bees ni Ife Nedbank . O ṣe akọbi Ajumọṣe rẹ nigbamii ni akoko yẹn bi aropo ni ijatil 2–1 si Lamontville Golden Arrows ni ọjọ 27 May 2017. Maart lo akoko 2018-19 l' awin pẹlu Cape Umoya United, nibiti o ti gba goolu wọle leeksn ninu ifẹsẹwọnsẹ merindinlogun. [2] Awon egbe agbabọọlu aajalelokun fi sile ko ma lo ni igba ooru 2020.

Sekhukhune United

àtúnṣe

Maart darapọ mọ Sekhukhune United ti National First Division lẹhin igba ti egbe agbabọọlu Pirates ti yonda re. O ṣe ipa pataki ninu igbega ẹgbẹ naa si South Africa Premier Division ni akoko yẹn, o gba goolu meta wọle ninu ifẹsẹwọnsẹ 28 liigi.

Ise okeere

àtúnṣe

A pe Maart si ẹgbẹ agbabọọlu orilẹ-ede South Africa fun 2021 COSAFA Cup . O gba goolu akọkọ rẹ wọle ni ọjọ 16 Oṣu Keje 2021 ninu ibori ifẹsẹwọnsẹ ologbele-ipari COSAFA pelu Mozambique, o si ṣere ni ipari bi Maart ṣe bori idije naa ni atẹle iṣẹgun ifiyaje 6–5 lori Senegal . O gba ifẹsẹwọnsẹ 6 o gba goolu kan so wọlé lakoko 2021 COSAFA Cup.

Awọn itọkasi

àtúnṣe
  1. Àṣìṣe ìtọ́kasí: Invalid <ref> tag; no text was provided for refs named auto
  2. Àṣìṣe ìtọ́kasí: Invalid <ref> tag; no text was provided for refs named sw

Ita ìjápọ

àtúnṣe
  • Yusuf Maart at WorldFootball.net

Àdàkọ:Sekhukhune United F.C. squad