Zain Asher
Zain Ejiofor Asher (bíi ni ọjọ́ kẹtàdínlógbon oṣù kẹjọ ọdún 1983) jẹ́ ọmọ orílẹ̀ èdè Nàìjíríà àti Britain, ó jẹ́ agbóhùnsáfẹ́fẹ́ fún CNN International ni ilẹ̀ New York City. Ó darapọ̀ mọ́ ilé iṣẹ́ CNN ni odun 2013.[1] Ó tún má ṣise fún Money Magazine.[2]
Zain Asher | |
---|---|
Fáìlì:Zain Asher.jpg | |
Ọjọ́ìbí | Zain Ejiofor Asher 27 Oṣù Kẹjọ 1983 Balham, London Borough of Wandsworth, England |
Ibùgbé | New York City, New York, U.S. |
Orílẹ̀-èdè | British, Nigerian |
Ẹ̀kọ́ | Keble College, Oxford University (BA) Columbia University (MS) |
Iṣẹ́ | Anchor, Journalist |
Ìgbà iṣẹ́ | 2006–present |
Àwọn olùbátan | Chiwetel Ejiofor (brother) |
Ìbẹ̀rẹ̀pẹ̀pẹ̀ ayé àti ètò-ẹ̀kọ́ rẹ̀
àtúnṣeWọn bíi ni Balham, London Borough of Wandsworth, England, àwọn òbí rẹ jẹ ọmọ orílẹ̀ èdè Nàìjíríà. Asher jẹ́ àbúrò sì Òṣeré Chiwetel Ejiofor.[3][4] Ó sì jẹ ọmọ ìlú Ezeagu ni ìpínlè Enugu ni ilẹ̀ Nàìjíríà. Ni ọdún 2005 Ashley lọ sí ilé ẹ̀kọ́ gíga Keble College ni Oxford University níbi tí ó ti kọ èdè Spanish àti French.[5] Ní ọdún tí ó tẹ̀le, ó parí ẹ̀kọ́ rẹ ni ilé ẹ̀kọ́ gíga Columbia University ni ibi tí ó ti kọ nípa ìmò ìròyìn.[6]
Iṣẹ́
àtúnṣeO darapọ̀ mọ́ ilé iṣẹ́ CNN ni oṣù kejì ọdún 2013. Kí ó tó darapọ̀ mọ́ CNN, ó ń sisé fún Money Magazine ni ibi tí ó ti kọ nípa ọrọ̀ owó fún wọn. Ó ti ṣíṣe fún New 12 Brooklyn gẹgẹ bí alaroye lórí telefiisionu.[7]
Àwọn Ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ "Quick Links". CNN. http://www.cnn.com/profiles/zain-asher-profile.
- ↑ Asher, Zain (1 July 2014). "Is Living with Mom and Dad Starting to Cramp Your Style? Take These Steps to Independence". Time. Archived from the original on 24 February 2015. https://web.archive.org/web/20150224032938/http://time.com/money/2941013/is-living-with-mom-and-dad-starting-to-cramp-your-style-take-these-steps-to-independence/.
- ↑ Mesure, Susie (27 January 2013). "Chiwetel Ejiofor: 'I find racial concepts fascinating'". London: The Independent. https://www.independent.co.uk/arts-entertainment/films/features/chiwetel-ejiofor-i-find-racial-concepts-fascinating-8468418.html. Retrieved 5 November 2013.
- ↑ "Quick Links". CNN.com. http://www.cnn.com/2014/03/02/showbiz/oscars-2014-winners-list/.
- ↑ "35 Years of Keble Women". keble.ox.ac.uk. Keble College, Oxford University. Archived from the original on 2019-03-02.
- ↑ "Quick Links". CNN.com. http://www.cnn.com/profiles/zain-asher-profile.
- ↑ "Quick Links". CNN. http://www.cnn.com/profiles/zain-asher-profile.