Zainab Ashadu
Zainab Ashadu je oludasile ile ise Zashadu ton se apo agbekowo lorisirisi to jasi pe awon ohun igbalode ni meremere, bi kase nkan pelu awo omi ati lilo aworan asa aye awon babawa tohunti fifi owo hun awo eran taamo si "leather" ni ede geesi towa lati apa Ariwa Naijiria. Awon eyan nife si ise owo arabinrin yii toje omo odun mejilelogbon.[1] Idi pataki nipe gbogbo ohun ti on lo je ti orile ilu wa atipe awon ohun wonyi ni apa ibi ti otiwa ni ilu Naijiria. Lati adugbo kan ni Fesitaki, nibi ti ariwo ero iranso tin dun ni gbogbo igba lati ma n ri opo eyan bi mefa toje onimo lori awon uhun meremere lodoodun ma n hun apo agbekowo bi igba (200) si odunrun (300).
Awon obi Ashadu wa lati apa Ariwa ile Naijiria. Apa Ariwa je ibi kan ti ohun to dara toje ojunigbese tiwa, leyi ti arabinrin onise ara yii fi n se apo owo ati apo agbekowo ti o n ta ni le okere fun owo iyebiye laarin $185 si $180. Awo eran wonyii wa lati ilu to tobi julo ni apa Ariwa Naijiria tamo si ilu Kano, ati awo ewure to wa lati Guusu/Ariwa ilu Sokoko lorile ede Naijiria, tohun ti awo ejola (Python skin) lati oko ejo (snake farm) ni agbegbe yi. Toyato si ti awon ile ise asaraloge ile Yuroopu to se pe ilu Naijiria ni won ti n ri eroja bi awo tosi je wipe won ma n run laro, Ashadu pin nu lati lo ogbon toun ti imo abalaye toje yo ilu Kano ti a si fi mo iran omo yoruba to mo nipe ise owo ni meremere.
Zainab Ashadu sope, "Ose pataki fun mi lati se ise ni ilana ti o mu aye derun". O tuni, "Mo n se ifowosowopo pelu awon ebi kekeke to mo awo run, awon eranko yi ni amin idamo, a n lo aro elewe pelu awon aro to fanimora lagbegbe". Arabinrin yi man ni ayo okan fun ise yi lakoko to ba lo se idunadura larin oja Mushin to wa ni inu ilu Eko (Lagos). Awon awo yi larinrin gaan … awo po lopo yanturu tojepe igbamin onisowo gan o ni oye bi awo se dara si. Awo etu wa to le dada pelu ti ewure ati agutan.
Gbogbo igba ti Zainab ba ti ra ohun elo ni awon emewa e man yipada si apo. Awon emewa e lo je onimo ise awo ti o gba amin eye lati apa Ariwa ni ilu Zaria. Ashadu je okan gboogi ninu awon omo Naijiria to pada wa le nitori ati gbe oro aje wa laruge lehin opo odun ilu okere. O lo igba ewe re ni ilu Eko, sugbon o je odo ni orile ede Londonu, Zainab se ise pupo ni be bi, awose, osere, olurajaati wiwa imo ekoo ayaworan. Ni odun 2010 ni o pada wasi ile Naijiria nigbati o gbiyanju pelu ifarada mo orisi ona bi a se n se owo. Arabinrin yi so ninu oro re pe, eniyan gbodo je alakikanju eda ko to le ni lakai to munadoko. Ose Pataki ki eyan ni agboye pelu ati ni ifarada si orisi ona bi a se n se owo leyi to je kokoro fun onisowo lati tesiwaju ni Naijiria.
Okan ninu awon ohun to tun se Pataki ni igbiyanju lati mo bi awon omo ise se n tesiwaju ninu awo reran, yato si ki a ma kanipa fun won lati faramo ohun ti a nko ni ile eko isaraloje. Opo eyan lo nife si ise owo re ti won si je olubara gidi. Igba min oma n taja fun awon ile ise aladani bi, ile itura, toun ti oja ori omi. Ni awon asiko kan seyin, oja won yi ama di tita ni ori ero alatagba, shoobu ipate ni Londonu, Miami, Dublin, Johannesburg ati Paris. Charlotte Ziegler to n se nkan meremere lo ma n ta apo ti Zainab ba se ni shoobu kan ta mo si Franck et Fils ni orile ede Farase.
Olutaja yi ni, "ori owun ma n wu ni gbogbo igba ti o ba ri ise awo ma le lo ti Zashadu ma n se. Okan Ashadu bale lori ise ton se, osi mo pe ayanmo ni ise to un n se. atipe ebun kan ni fun owun lati ma se asa lorisirisi. "Oni awon eyan nife si olu ilu Afirika, ati pe Afirika je ibi nkan tuntun ti n sele leyi ti opo eyan ma n fe se". Itoka si leleyi fun opolopo eniyan - won ma n ni nkan ilu ile Afirika ni, odara osi rewa, yio peepeepee asii tojo. Atipe, nkan ti owa lati ile okere ni.
Àwọn ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ "Zainab Ashadu: The brains behind Nigerian designer handbag maker Zashadu". African Business Central. 2014-12-25. Archived from the original on 2018-10-03. Retrieved 2018-08-25.