Zani Barnard
Zani Barnard (tí a bí 15 òṣù Kẹ́ta 1999) jẹ́ òṣèré tẹnisi South Africa ti kò ṣiṣẹ́. O ṣeré fún South Africa lórí
Orílẹ̀-èdè | Gúúsù Áfríkà |
---|---|
Ọjọ́ìbí | 15 Oṣù Kẹta 1999 Witbank, South Africa |
Ọwọ́ ìgbáyò | Right-handed (two-handed backhand) |
Kọ́lẹ̀jì | MTSU |
Ẹ̀bùn owó | $1,879 |
Ẹnìkan | |
Iye ìdíje | 6–7 |
Grand Slam Singles results | |
Open Austrálíà Ọmọdé | 1R (2016) |
Ẹniméjì | |
Iye ìdíje | 6–5 |
Grand Slam Doubles results | |
Open Austrálíà Ọmọdé | 1R (2016) |
Àwọn Ìdíje Ẹgbẹ́ Agbáyò | |
Fed Cup | 0–1 |
Last updated on: 31 August 2020. |
Barnard ní ìpò ìṣẹ́ gíga ITF juniors tí 73, tí ó wáyé ní ọjọ́ 29 oṣù kejì 2016.
Ó bẹ̀rẹ̀ ìkẹ̀kọ̀ ní Middle Tennessee State University (MTSU), ni ọdún 2017 pẹlú arábìnrin Ìbejì rẹ̀ Lee .