Zaynab Alkali (tí a bí ní ọdún 1950) jẹ́ ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà tí wọ́n sínú ìdílé Tura-Mazila ní Ìpínlẹ̀ Bọ̀rnó.[2] Ó lọ ilé-ìwé Queen Elizabeth Secondary School ti ìlú Ilorin kí ó tó tẹ̀síwájú ní Yunifásítì Àmọ́dù Béllò (ABU), Zaria àti ní Yunifásítì Bayero ti Kano (BUK) láti gba àmì-ẹ̀yẹ Dokita(PhD) nínú ìmò Inglisi.[2]

Zaynab Alkali
Ọjọ́ìbí1950
Tura-Wazila, Ìpínlè Borno[1]
Orílẹ̀-èdèNigerian
Ẹ̀kọ́Yunifásitì Bayero ti Kano
Gbajúmọ̀ fúnfirst woman novelist from Northern Nigeria
Olólùfẹ́Mohammed Nur Alkali
Àwọn ọmọÀwọn ọmọ mẹ́fà

Ìpìlẹ̀ àti Ẹ̀kọ́ rẹ̀

àtúnṣe

A bí Alkali ní Tura-Wazila ní ìpínlẹ̀ Borno ní ọdun 1950. Ó kàwé gboyè ní Yunifásítì Báyéró ti ìpínlẹ̀ Kano pẹ̀lú àmì-ẹ̀yẹ BA ní ọdún 1973.[3] Ó gba àmì-ẹ̀yẹ Dókítá nínú ìmò nípa ilẹ̀ Áfríkà ní Yunifásitì kan náà kí ó tó padà di adarí ilé-ìwé Shekara Girls' Boarding School. Ó padà di olùkọ́ni nínú ìmọ̀ èdè Inglisi ní àwọn Yunifásitì méjì ní Nàìjíríà.[4]

Àwọn Ìtọ́kasí

àtúnṣe
  1. Galleria, Nigeria. "Nigeria Personality Profile". Nigeria Galleria. Galleria Media Limited. Retrieved 11 March 2019. 
  2. 2.0 2.1 Kabir, Hajara Muhammad (2010). Northern women development. Nigeria. ISBN 978-978-906-469-4. OCLC 890820657. 
  3. Margaret Busby, Daughters of Africa, London: Cape, 1992, p. 782.
  4. Professor Henry Louis Gates, Jr.; Professor Emmanuel Akyeampong; Steven J. Niven (2 February 2012). Dictionary of African Biography. OUP USA. pp. 177–178. ISBN 978-0-19-538207-5. https://books.google.com/books?id=39JMAgAAQBAJ&pg=PA301.