Zayyad Ibrahim
Olóṣèlú
Zayyad Ibrahim (ojoibi 1965) je olóṣèlú ọmọ Nàìjíríà. Ó sìn gẹ́gẹ́ bí ọmọ ẹgbẹ́ tó ń ṣojú ẹkùn ìpínlẹ̀ Ìgabi Federal Constituency ti ìpínlẹ̀ Kaduna nínú ilé ìgbìmọ̀ aṣòfin 9th láti ọdún 2019 sí 2023. [1] [2]
Zayyad Ibrahim | |
---|---|
Member of the House of Representatives of Nigeria from Kaduna State | |
In office 2019–2023 | |
Arọ́pò | Mohammed Hussaini Jallo |
Constituency | Igabi |
Àwọn àlàyé onítòhún | |
Ọjọ́ìbí | 22 March 1965 |
Ẹgbẹ́ olóṣèlú | All Progressives Congress |
Occupation | Politician |
Igbe ayé ibẹrẹ
àtúnṣeZayyad Ibrahim ni àbí ni ọjọ kejìlelógún oṣù kẹta ọdun 1965 láti ìlú Kaduna State.[3]
Ìrìnàjò òṣèlú
àtúnṣeNi inú ètò idibo atundi ọdún 2023 Ibrahim tún dije labẹ ẹgbẹ òṣèlú All Progressive Congress tí òsì fi idiremi sì ọwọ alátakò rẹ tinse Hussaini Muhammad Jallo tí ẹgbẹ òṣèlú Peoples Democratic Party.[4][5]
Awọn itọkasi
àtúnṣe- ↑ https://citizensciencenigeria.org/public-offices/persons/zayyad-ibrahim-0
- ↑ https://sub-sahara.news.blog/2021/07/12/hon-zayyad-impact-on-politics-is-second-to-none/
- ↑ https://www.constrack.ng/lawmaker_details?id=152
- ↑ https://von.gov.ng/kaduna-re-run-election-apc-pdp-win-two-seats-each-in-4-lgas/
- ↑ https://www.channelstv.com/2024/02/04/apc-pdp-candidates-emerge-winners-in-kaduna-bye-election/amp/