Zee Bangla jẹ́ ìkànnì tẹlifíṣàn awòsáwó lédè Bengali l'órílẹ̀-èdè India ti ilé-iṣẹ́ amóhùnmáwòrán Zee Entertainment Enterprises.

Wọ́n fi ìkànnì náà lọ́lẹ̀ lọ́jọ́ kẹ́ẹẹ́dógúm oṣù kẹsàn-án ọdún 1999 gẹ́gẹ́ bí Alpha TV Bangla, pẹ̀lú Alpha TV Marathi, Alpha TV Telugu àti Alpha TV Punjabi.[1] It was the first Bengali-language satellite television channel in India.[2]

Nígbà tí ó di ọjọ́ kẹsàn-án oṣù kẹfà ọdún 2011,gbogbo ìkànnì tí ó wà lórí pẹpẹ Zee ṣe àtúntò àti àtúnṣe pẹ̀lú àmà ìdámọ̀ tuntun tí ó dàbí oǹkà dípò álúfábẹ́ẹ̀tìZ.[3][4][5]Àdàkọ:Importance inline

Lọ́dún 2019, Samrat Ghosh di adarí ìkànnì náà.[6]Àdàkọ:Importance inline Wọ́n ṣàfihàn àwòrán adámọ̀ lásìkò Sa Re Ga Ma Pa lọ́jọ́ keje oṣù kẹwàá ọdún 2018.[7][8][9] L'óṣù kejì ọdún 2020, ó wà lára àwọn ìkànnì ńlá tẹlifíṣàn ní Indian tí àwọn ènìyàn ń wò jù.[10]

L'ọ́gbọ̀jọ́ oṣù kẹsàn-án ọdún 2021, Bangladesh pàṣẹ láti f'ọfin de gbogbo ìkànnì tẹlifíṣàn ilẹ̀-òkèèrè n'ílùú wọn, Zee Bangla wà lára wọn, pàápàá jùlọ àwọn ìkànnì tẹlifíṣàn aṣòwò-jèrè.[11] Lẹ́yìn ọ̀sẹ̀ méjì, Zee Bangla bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ agbóhùmgbáwòrán s'áfẹ́fẹ́ padà ní Bangladesh, ṣùgbọ́n láìṣètò apowósápò.[12]

Àwọn ètò tí wọ́n ń ṣe lọ́wọ́ llọ́wọ́

àtúnṣe

Àwọn eré-oníṣe

àtúnṣe
Title Premiere date
Puber Moyna 24 June 2024
Ke Prothom Kachhe Esechi[13] 27 May 2024
Jagaddhatri 29 August 2022
Phulki 12 June 2023
Neem Phooler Madhu 14 November 2022
Kon Gopone Mon Bheseche 18 December 2023
Diamond Didi Jindabad 24 June 2024
Mithijhora 27 November 2023
Jogomaya 11 March 2024

Àwọn ètò ajẹ́máyé

àtúnṣe
Title Premiere date
Didi No. 1 Season 9 14 February 2022
Randhane Bandhan 20 May 2024
Sa Re Ga Ma Pa Bangla 2024 2 June 2024

Àwọn ètò tí wọ́n ń ṣe nígbà kan rí

àtúnṣe

Àwọn ètò ajẹméwì

àtúnṣe

Àwọn ère-oníṣe

àtúnṣe

Àwọn ètò àwòrán ajẹmẹ́ranko

àtúnṣe

Àwọn ètò bóṣeńṣẹ̀lẹ̀

àtúnṣe

Àwọn Ìtọ́kasí

àtúnṣe
  1. "ZEE TV TIES UP TRANSPONDER DEAL WITH ASIASAT". Indian Television. 
  2. Television in India: Satellites, Politics and Cultural Change. Routledge. 2008. pp. 158–160. ISBN 978-1-134-06213-3. https://books.google.com/books?id=Ep2iOKyNuBMC&pg=PA158. 
  3. "Zee channels to sport new logos". 28 March 2005. https://www.business-standard.com/article/companies/zee-channels-to-sport-new-logos-105032801072_1.html. 
  4. "Remembering Soumitra Chatterjee, Bengali cinema's alt superstar". Zee News. 
  5. "Zee Bangla makes a comeback with fresh content". Afaqs. 
  6. "New roles for Amit Shah and Samrat Ghosh at Zee Entertainment Enterprises – Exchange4media". exchange4media (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2021-02-25. 
  7. "Zee TV unveils its brand new logo and philosophy, 'Aaj Likhenge Kal'". exchange4media. 
  8. "Zee Bangla dons new look". exchange4media. 
  9. "Zee Bangla airs fresh episodes of fiction shows from June 15". bestmediainfo. 16 June 2020. 
  10. "BARC week 6: Four Zee regional channels lead regional markets". Indian Television. 2020-02-22. Retrieved 2020-10-20. 
  11. "দেশে বিজ্ঞাপনসহ বিদেশি টিভি চ্যানেলের সম্প্রচার বন্ধ". bdnews24.com (in Bengali). Retrieved 2021-10-16. 
  12. "Zee Bangla broadcast resumes in Bangladesh without ads". bdnews24.com. Retrieved 2021-10-16. 
  13. ""Ke Prothom Kachhe Esechi TV Serial Online - Watch Tomorrow's Episode Before TV on ZEE5"". https://www.zee5.com/tv-shows/details/ke-prothom-kachhe-esechi/0-6-4z5566925. 
  14. "Adrit Roy and Darshana Banik pair up for 'Lockdown Diary'". The Times of India. 
  15. "Read know about Zee Bangla's Amloki". Tellychakkar. 
  16. "Ashtami: Durjoy sends goons to kill Ashtami; Ayushmaan comes to the rescue". The Times of India. ISSN 0971-8257. https://timesofindia.indiatimes.com/tv/news/bengali/ashtami-durjoy-sends-goons-to-kill-ashtami-ayushmaan-comes-to-the-rescue/amp_articleshow/109436884.cms. 
  17. "চেনা মানুষের অচেনা মুখোশের কাহিনি নিয়ে আসছে 'ছদ্মবেশী'". Sangbad Pratidin (in Bengali). 
  18. "Nabanita Das-Indrajit Chakraborty starrer ‘Deep Jwele Jai’ to have its Hindi remake?". The Times of India. 
  19. "প্রথম বার 'ক্ষীরের পুতুল' আসছে ছোট পর্দায়". Anandabazar (in Bengali). 
  20. 20.0 20.1 20.2 "Alpha Bangla to woo masses with new fare". Indian Television. 
  21. "Zee Bangla launches a new mega serial 'RASHI'". 
  22. "Saswata to play key role in Zee Bangla’s new reality show Apur Sansar". Tellychakkar.