Zemzem Ahmed Deko ni a bini ọjọ kẹta dinlọgbọn, óṣu December ni ọdun 1984 ni ilu Asella jẹ elere sisa ti Steeplechase ati ti óju ọna ti órilẹ ede Ethiopia. Arabinrin naa jẹ ọkan lara awọn elere sisa ti steeplechase to pegede julọ ni ilẹ Ethiopia[1].

Zemzem Ahmed
Ahmed at the 2014 Paris Marathon
Òrọ̀ ẹni
Orúkọ kíkúnrẹ́rẹ́Zemzem Ahmed Deko
Ọmọorílẹ̀-èdè Ethiopia
Ọjọ́ìbí27 Oṣù Kejìlá 1984 (1984-12-27) (ọmọ ọdún 40)
Asella, Ethiopia
Height1.70 m (5 ft 7 in)
Weight53 kg (117 lb)
Sport
Erẹ́ìdárayáAthletics (sport)
Event(s)Steeplechase
ClubBanks SC (ETH)

Àṣèyọri

àtúnṣe

Zemzem ṣoju Ethiopia ninu Olympics ti Summer to waye ni Beijing ni ọdun 2008 to si kopa ni steeplechase ti awọn óbinrin ti ẹgbẹrun mẹta Metre[2]. Ni ọdun 2009, Arabinrin naa kopa ninu idije agbaye ti ere sisa to si gbe ipo kẹwa ninu steeplechase pẹlu ere ti iṣẹju 9:22.64. Ni ọdun 2012, Arabinrin naa kopa ninu Marathon ti Frankfurt nibi to ti gbe ipo kẹfa pẹlu wakati 2:27:12[3].

Itọkasi

àtúnṣe
  1. Zemzem Ahmed Profile
  2. Women's 3000m Steeplechase
  3. Frankfurt Marathon