Zenande Mfenyana
Zenande Mfenyana (bíi ni ọjọ́ kọkànlá oṣù kẹwàá ọdún 1985[1]) jẹ́ òṣèré àti mọ́dẹ́lì ni orílẹ̀ èdè South Áfríkà. Ó gbajúmọ̀ fún ipá Noluntu Memela tí ó kó nínú eré Generations. Wọ́n bíi Mfenyana sì ìlú Johannesburg. Ó lọ sí ilé ẹ̀kọ́ Queenstown Girl's High School kí ó tó tẹ̀ síwájú sí ilé ẹ̀kọ́ gíga tí University of Pretoria níbi tí ó tí gboyè nínú ìmò Dírámà.
Zenande Mfenyana | |
---|---|
Ọjọ́ìbí | Zenande Feziwe Mfenyana 11 Oṣù Kẹ̀wá 1985 Kagiso, Gauteng |
Orílẹ̀-èdè | South Africa |
Iléẹ̀kọ́ gíga | University of Pretoria (BA in Drama) |
Iṣẹ́ | Actress |
Ìgbà iṣẹ́ | 2006–present |
Notable work | Generations |
Iṣẹ́
àtúnṣeMfenyana di gbajúmọ̀ ni ọdún 2011 fún ipá Noluntu Memela tí ó kó nínú eré Generations èyí tí Mfundi Vundla gbé jáde.[2] Ní oṣù kìíní ọdún 2015, ó kó ipa Reba nínú eré Ashes to Ashes pẹ̀lú àwọn gbajúmọ̀ òṣèré bíi Tina Jaxa àti Menzi Ngubane.[3] Ní oṣù kejì, ọdún 2017, ó kó ipá Goodness Mabuza nínú eré The Queen.[4]
Àṣàyàn àwọn eré rẹ̀
àtúnṣeOdun | Akori ere naa | Ipa ti o ko | |
---|---|---|---|
Generations | Noluntu Memela | ||
Ashes to Ashes | Reba Namane | ||
Igazi[5] | Babalwa | ||
MTV Shuga (Down South) | Cynthia Vilakazi | ||
2017 | The Queen | Goodness Mabuza |
Àwọn Ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ Adeaga Favour (3 July 2019). "Zenande Mfenyana biography: age, boyfriend, husband, parents, hairstyles, pictures and net worth". briefly.co.za.
- ↑ World, Sunday (Nov 9, 2014). "Zenande Mfenyana moves on after Generations". SundayWorld. Archived from the original on July 3, 2018. Retrieved Aug 11, 2017.
- ↑ "Zenande Mfenyana biography | Tvsa". tvsa.co.za.
- ↑ Kekana, Chrizelda (Apr 18, 2017). "The Queen's Goodness is the 'perfect fit' for Zenande Mfenyana". SundayWorld. Archived from the original on October 9, 2018. Retrieved Aug 11, 2017.
- ↑ Madlela, Mayibongwe (Aug 11, 2017). "Melodrama Igazi back with more chaos". The Chronicle. Retrieved Aug 11, 2017.