Zokela
Zokela jẹ́ ẹgbẹ́ olórin kan ní orílẹ̀ èdè Central African Republic, ó jẹ́ ọ̀kan lára àwọn ẹgbẹ́ olórin tí ó gbajúmọ̀ jù lórílẹ̀ èdè náà. Ẹgbẹ́ náà ma ń kọ àwọn orin tí à ń pè ní Zokela, àwọn orin Zokela gbajúmọ̀ ní orílẹ̀ èdè náà ni àwọn ọdún 1980s.[1] Ẹgbẹ́ olórin náà tí wọ́n fi Bangui ṣe ilé ma ń lọ guitar àti ìlù ìgbàlódé pẹ̀lú àwọn "ohùn ayẹyẹ àti ijó òkú Lobaye".[2]
Àwọn Ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ John Shepherd (2005). Continuum encyclopedia of popular music of the world. Continuum. p. 264. ISBN 978-0-8264-7436-0. https://books.google.com/books?id=jhUKAQAAMAAJ.
- ↑ Michelle Robin Kisliuk (1998). Seize the Dance!: BaAka Musical Life and the Ethnography of Performance. Oxford University Press. p. 182. ISBN 978-0-19-514404-8. https://books.google.com/books?id=Wo0qwaGbkgoC&pg=PA182.