Àbàwọn (Stigma) (Fiimu ọdún 2013)
Abawọn (Stigma) jẹ́ eré oníṣe lati orilẹ-èdè Nàìjíríà tí a gbé jáde ni ọdun 2013. Ere oniṣe yii da lori ìdẹ́yẹ sí ti àwọn eniyan ti arun kogboogun, EEDI n ba fínra n doju kọ. Abúlé kan ni Ipinle Rivers ni ète eré yii da le. Diminas Dagogo ni oludari eré naa nigbati awọn gbajugbaja osere bii Jackie Appiah, Hilda Dokubo àti Emeka Ike kopa ninu ere naa. Ile-iṣẹ elétò Ilera ti Ìpínlẹ̀ Rivers ni o se agbejade ere naa.
Stigma | |
---|---|
Fáìlì:Stigma (2013 film) theatrical release poster.jpeg | |
Adarí | Diminas Dagogo |
Olùgbékalẹ̀ | Rivers State Ministry of Health 13Fatman Int'l Limited |
Àwọn òṣèré | |
Olóòtú | Siem Nkula and Eileen De Klerk |
Ilé-iṣẹ́ fíìmù | 13Fatman Films |
Déètì àgbéjáde |
|
Àkókò | 96 minutes |
Orílẹ̀-èdè | Nigeria |