Àdàkọ:Ayoka Ose/7
Orile-ede Olominira Benin je orile-ede ni Apa Ilaoorun Afrika ti a mo tele gege bi Dahomey (titi de odun 1975). O ni bode pelu Togo ni apa ilaoorun, Naijiria ni apa iwoorun, ati Burkina Faso ati Nijeri ni ariwa. Ni guusu o jasi Etiodo Benin (Bight of Benin). Botileje pe oluilu re je Porto Novo ibujoko ojoba wa ni [[Kutonou]. "Benin" gege bi oruko re ko ni ohunkohun se pelu Ilẹ̀ọba Benin (tabi Benin City). Oruko re tele je Dahomey ki a to yi si Orile-ede Agbajumo Olominira Benin ni odun 1975 nitori egbe odo to wa eyun Etiodo Benin. Won mu oruko yi nitoripe ko fi s'egbe kan larin gbogbo awon eya eniyan bi adota ti won wa ni ile Benin. Dahomey je oruko iluoba Fon ti ayeijoun, nitori eyi won ro pe ko to.