Àfin Al-Gawhara
Al-Gawhara Palace (Lárúbáwá: قصر الجوهرة Qaṣr al-Gawhara), jẹ́ àfin àti musíọ́mù ní Cairo, Egypt. Àfin náà wà ní gúúsù Mọ́sálásíi Muhammad Ali ní Cairo Citadel. Muhammad Ali Pasha ni ó ṣe àfilọ́lẹ̀ ní ọdún 1814.
Àwọn àkọ́lé láti oríṣiríṣi orílẹ̀ èdè bi Gríkì, Turks, Bulgaria àti Albania ni ó kọ.[1]:17 Ní ọdún
In 1822, iná ba apá kan àfin náà jẹ́, iná yẹn jó fún ọjọ́ méjì, àwọn ibi tí ó sì bàjẹ́ jẹ́ àwọn ibi tí a fi pákọ́ ṣe, Muhammad padà fe ilé náà nígbà tí ó kó apá míràn mọ, wọ́n fi ìṣàn omi, òdòdó àti àwọn míràn tings."[1]
Lẹ́yìn ọdún méjì, ní ọdún 1824, iná tún ba àfin náà jẹ́. Muhammad Ali sì tún tun ṣe.[1]
Àwọn Ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ 1.0 1.1 1.2 Johnston, Shirley. Egyptian Palaces and Villas. New York: Abrams. ISBN 0-8109-5538-5. Photographs by Sherif Sonbol