Àgbàdo

Odun,aleseje,ale fi se ogi fun eko mimu

Àgbàdo (Látìnì: Zea mays) ni ó jẹ́ óuńjẹ jij́ẹ oní hóró tí àwọn ènìyàn ilẹ̀ apá Gúúsù ilẹ̀ Mexico ṣe àwárí rẹ̀ ní ǹkan bíi egberun mewa odun seýin..[1][2][3][4] Igi àgbàdo ma ń yọ ewé sooro, tí ó sì ma ń yọ ìrùkẹ̀rẹ̀ ní ọwọ́ òkè èyí tí ó ma ń ṣe atọ́nà fún yíyọ ọmọ àgbàdo[5][6] . Àwọn onímọ̀ sáyẹ́nsì fẹ́ràn láti máa pèé ní Maize (àgbàdo) nítorí wípé orúkọ yí ni ó gbajúmọ̀ jùlọ fún irúfẹ Oúnjẹ oníhóró yí, tí ó sì ní it̀umọ̀ oríṣiríṣi lọ́dọ̀ àwọn ènìyàn ní orílẹ̀ àgbáyé.

Àgbàdo
Illustration showing male and female maize flowers
Ìṣètò onísáyẹ́nsì [ edit ]
Ìjọba: Ọ̀gbìn
Clade: Vascular plant
Clade: Flowering plant
Clade: Monocotyledon
Clade: Commelinids
Ìtò: Poales
Ìdílé: Poaceae
Ìbátan: Zea (plant)
Irú:
Z. mays
Ìfúnlórúkọ méjì
Zea mays
Zea mays "fraise"
Zea mays "Oaxacan Green"
Zea mays "Ottofile giallo Tortonese”



  1. "The Evolution of Corn". University of Utah HEALTH SCIENCES. Archived from the original on 13 July 2019. Retrieved 2 January 2016. 
  2. Benz, B. F. (2001). "Archaeological evidence of teosinte domestication from Guilá Naquitz, Oaxaca". Proceedings of the National Academy of Sciences 98 (4): 2104–2106. Bibcode 2001PNAS...98.2104B. doi:10.1073/pnas.98.4.2104. PMC 29389. PMID 11172083. //www.pubmedcentral.nih.gov/articlerender.fcgi?tool=pmcentrez&artid=29389. 
  3. "The Evolution of Corn". University of Utah HEALTH SCIENCES. Archived from the original on 13 July 2019. Retrieved 2 January 2016. 
  4. Benz, B. F. (2001). "Archaeological evidence of teosinte domestication from Guilá Naquitz, Oaxaca". Proceedings of the National Academy of Sciences 98 (4): 2104–2106. Bibcode 2001PNAS...98.2104B. doi:10.1073/pnas.98.4.2104. PMC 29389. PMID 11172083. //www.pubmedcentral.nih.gov/articlerender.fcgi?tool=pmcentrez&artid=29389. 
  5. "Please settle a dispute. Is sweet corn a vegetable or a grain? What is the difference? How about field corn? - eXtension" (in en). USDA National Institute of Food and Agriculture, New Technologies for Ag Extension project. http://articles.extension.org/pages/36971/please-settle-a-dispute-is-sweet-corn-a-vegetable-or-a-grain-what-is-the-difference-how-about-field-. 
  6. Chodosh, Sara (8 July 2021). "The bizarre botany that makes corn a fruit, a grain, and also (kind of) a vegetable". Popular Science. Retrieved 24 February 2022.