Àgbègbè Ìwọ̀-ọọ̀rùn, Rwanda
Eastern Province (Faransé: Province de l'Est; Duki: Oostelijke Provincie) ni agbègbè tí ó tóbi jù, tí ó sì ní àwọn olùgbé tí ó pọ̀ jù nínú àwọn agbègbè márùn-ún tí ó wà ní Rwanda. Wọ́n da kalẹ̀ ní oṣù kínní ọdún 2006 gẹ́gẹ́ bi ara àwọn ǹkan tí ìjọba Rwanda láti pín agbára kakiri àwọn agbègbè ni Rwanda.
Agbègbè Eastern Intara y'Iburasirazuba | |
---|---|
Country | Rwanda |
Capital | Rwamagana |
Districts | |
Government | |
• Governor | CG Emmanuel K. GASANA (2021-) |
Area | |
• Province | 9,458 km2 (3,652 sq mi) |
Population (2022 census)[2] | |
• Province | 3,563,145 |
• Density | 380/km2 (980/sq mi) |
• Urban | 745,935 |
• Rural | 2,817,210 |
Other settlements | Kibungo, Nyagatare, Nyamata, Gahini, Kabarore, Kagitumba |
HDI (2021) | 0.526 [3] low · 2nd of 5 |
Agbègbè náà pín sí ìletò méje: Bugesera, Gatsibo, Kayonza, Ngoma, Kirehe, Nyagatare àti Rwamagana. Rwamagana ni Olú-ìlú agbègbè náà.
Akagera National Park wà ní agbègbè yí.
Àtòjọ àwọn ìletò ní agbègbè ìlà oòrùn Rwanda nípa iye àwọn olùgbé wọn(2012)
àtúnṣeIpò wọn ní Eastern Province Districts, 2012[4] |
Ipò wọn ní Rwanda Districts, 2012 |
Ìletò |
Àwọn olùgbé ibẹ̀ ní 15 August 2012 |
Àwọn olùgbé ibẹ̀ ni 15 August 2002 |
Ìyàtọ̀ nínú àwọn olùgbé ni 2002 sí 2012 (%) |
Population Density 2012 (km2) |
Population Density Rank, Eastern Province 2012 |
---|---|---|---|---|---|---|---|
1 | 2 | Nyagatare | 466,944 | 255,104 | 83.0 | 243 | 6 |
2 | 3 | Gatsibo | 433,997 | 283,456 | 53.1 | 275 | 5 |
3 | 9 | Bugesera | 363,339 | 266,775 | 36.2 | 282 | 4 |
4 | 10 | Kayonza | 346,751 | 209,723 | 65.3 | 179 | 7 |
5 | 13 | Ngoma | 340,983 | 235,109 | 44.0 | 390 | 2 |
6 | 15 | Kirehe | 338,562 | 229,468 | 48.6 | 288 | 3 |
7 | 26 | Rwamagana | 310,238 | 220,502 | 40.7 | 455 | 1 |
Àpapò | - | Agbegbe ìlà oòrùn | 2,660,814 | 1,700,137 | 53.0 | 275 | - |
Àwọn Ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ Area Calculation (see below)
- ↑ Citypopulation.de Population of Eastern Province
- ↑ "Sub-national HDI - Area Database - Global Data Lab". hdi.globaldatalab.org (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 8 August 2021.
- ↑ "2012 Population and Housing Census (Provisional Results) | National Institute of Statistics Rwanda". Archived from the original on 6 December 2012. Retrieved 2012-12-06. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help)