Àjakálẹ̀ Àrùn COVID-9 ní Orílẹ̀-èdè Cape Verde
Àjàkálẹ̀ Àrùn COVID-9 dé orílẹ̀-èdè Cape Verde ní oṣù Kẹ́ta ọdún 2020.[3]
Àjakálẹ̀ Àrùn COVID-9 ní Orílẹ̀-èdè Cape Verde | |||||||||
---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|
| |||||||||
Àrùn | COVID-19 | ||||||||
Irú kòkòrò èràn | SARS-CoV-2 | ||||||||
Ibi | Cape Verde | ||||||||
Arrival date | 20 March 2020 (4 years, 8 months, 1 week and 6 days) | ||||||||
Gbogbo iye àwọn ẹ̀sùn | 2,258 (as of 26 July)[2] | ||||||||
Active cases | 873 (as of 26 July) | ||||||||
Iye àwọn tí ara wọn ti yá | 1,363 (as of 26 July) | ||||||||
Iye àwọn aláìsí | 22 (as of 24 July) | ||||||||
Official website | |||||||||
COVID 19 — Corona Vírus - Official site about COVID-19 in Cape Verde |
Bí ó ṣe bẹ̀rẹ̀
àtúnṣeNí ọjọ́ Kejìlá oṣù Kíní ọdún 2020, Àjọ ìṣọ̀kan tí ó ń rí sí ìlera ní àgbáyé fìdí àrùn Kòrónà tí a tún ń pè ní Kofid-19 ní orílẹ̀-m àgbáyé ní ọjọ́ Kejìlá oṣù Kínní ní ọdún 2020. Tí wọ́n sì fìdí rẹ̀ múlẹ̀ wípé àrùn yí bẹ̀rẹ̀ ní ìlú kan tí wọ́n ń pè ní Wuhan, ní ẹkùn Hubei ní orílẹ̀-èdè China. Àmọ́ ó tó ọjọ́ Kẹtalélọ́gbọ̀n oṣù Kejìlá ọdún 2019 kí wọ́n tó fi tó àjọ ìṣòkan àgbáyé létí.[4][5]
Wọ́n tún fìdí rẹ̀ múlẹ̀ siwájú si wípé bí àrùn yí bá ti mú ènìyàn, oun ni ó ń fa ìfúnpinpin ní ní inú káà ọ̀fun ati àyà, tí ó sì ma ń fa kàtá tàbí kí ènìyàn ó ma wú ikọ́ tàbí sín léra léra. Iye ìjàmbá tí àrùn Kòrónà ti fà lágbáyé kéré sí iye ìjàmbá tí àìsàn àrùn ọ̀fun SARS ti fà láti ọdún 2003. Àmọ́ iye àwọn ènìyàn tí wọ́n tó àrùn Kòrónà látàrí ríràn tí ó ń ràn kálẹ̀ ti.pọ̀ ju ti SARS lọ, bí ó ti lẹ̀ jẹ́ wípé ìtànkálé àrùn COVID-19 ń gbópọn si lójojúmọ́ tí ó sì ti ṣekú pa ọ̀pọ̀lọpò ènìyàn lágbáyé,[6][7][8][6] Model-based simulations for Cape Verde suggest that the 95% confidence interval for the time-varying reproduction number R t has been fluctuating around 1.2 since April 2020.[9]
Àwọn àsìkò kọ̀ọ̀kan tí ò ṣẹlẹ̀
àtúnṣeOṣù Kẹta ọdún 2020
àtúnṣeNí ogúnjọ́ oṣù kẹta, orílẹ̀-èdè Cape Verde ní akọsílẹ̀ COVID-9 akọ́kọ́, tí ẹni tí ó kó arùn náà jẹ́ ẹni ọdún méjìdínlọ́gọ́ta tí ó sì tún jẹ́ ọmọ orílẹ̀-èdè United Kingdom.[10][11] Ní ọjọ́ kejì, wọ́n tún ní akọsílẹ̀ méjì míràn, tí àwọn àrùn náà mú jẹ́ àrìnrì-àjò afẹ́ láti United Kingdom tí ọjọ́ orí ẹnì Kíní jẹ́ ọdún méjìdínlọ́gọ́ta tí ẹnìkejì sì jẹ́ ọmọ ọgọ́ta ọdún. Àwọn méjèjì yí ati ẹni akọ́kọ́ ni wọ́n jọ wà ní Boa Vista[12] The first death was announced[13] Ní ọjọ́ karùndínlọ́g ọ̀n oṣù kẹta, wọ́n tún ní akọsílẹ̀ ẹlẹ́mẹrin tí aláìsàn naa jẹ́ ẹni ọdún mẹ́tàlélógójì, tí ó sì jẹ́ ọmọ.orílẹ̀-èdè Cape Verde tí ó darí wálé láti Europe, tí wọ́n ṣì ṣàyẹ̀wò fun ní olú-ìlú Praia, ní erékùṣù Santiago.[14][15]Ní ọjọ́ kejì,Mínísítà fún ètò ìlera ní orílẹ̀-èdè Cape Verde kéde rẹ̀ wípé ìyàwó ẹni akọ́kọ́ tí ó ní arùn Kòrónà náà ti fara káṣá àìsàn náà pẹ̀lú. Tí obìnrin naa sì jẹ́ ẹnikẹ́ni akọ́kọ́ tí yóò ní àrùn náà láì rin ìrìn-àjò kan kan. [16] Wọ́n ní akọsílẹ̀ Karùún ní ìparí oṣù Karùún ọdún, 2020, nígbà tí ènìyàn kan ṣoṣo ti papò dà tí ó sì ṣẹ́ ku àwọn mẹ́rin dondo.[17]
Oṣù Kẹ́rin ọdún 2020
àtúnṣeNínú oṣù Kẹ́rin, wọ́n ti ní akọsílẹ̀ ọgọ́rún kan ó lé mẹ́rìndínlógún mìíràn, tí apapọ̀ iye ènìyàn tí ó ti ní àrùn yí ti gùnkè sí ọgọ́rùún kan ó lé mọ́kandínlógún. Kò sí ẹlòmíràn tó kú mọ́ yàtọ̀ sí ẹni akọ́kọ́ tó kú ,nígbà tí àwọn mẹ́rin rí ìwòsàn gbà tí wọ́n sì padà sílé wọn. Ó wá ku àwọn ènìyàn ọgọ́rùún kan ati mẹ́rìndínlógún tí àrùn náà ṣì wà lára wọ níparí oṣù kẹrin.[18]
Oṣù Karùún ọdún 2020
àtúnṣeNínú oṣù Karùún, orílẹ̀-èdè Cape Verde tún ní akọsílẹ̀ ènìyàn tí iye wọn tí ọgọ́rùún mẹ́ta ati mẹ́rìnlélógún tí wọ́n tún fara kó àrùn náà. Àwọn mẹ́rin ló ṣaláìsí, nígbà tí àwọn ènìyàn ọgọ́rùún kan ati mọ́kàndínlọ́gọ́sàán gba ìwòsàn tí wọ́ sì lọ sí Ilé wọn láyọ̀. Iye àwọn tó kù tí wọn kò tí gbádùn jẹ́ igba ó dín méje ènìyàn.[19]
Oṣù Kẹfà ọdún 2020
àtúnṣeCape Verde ní akọsílẹ̀ ènìyàn tí ó tó ọgọ́rùún mẹ́jọ ó dín mẹ́jọ tí wọ́n ti ní arùn COVID-9, tí ó mú kí iye àwọn aláìsàn náà lápapọ̀ ó jẹ́ ẹgbẹ̀rún kan àti ọgọ́rùún méjì ó lé méjìlélógún. Iye àwọn tí ó kú láti ìbérẹ̀ jẹ́ mẹ́ẹ̀ẹ́dógún, nígbà tí ye àwọn ènìyàn tó rí ìwòsàn gbà jẹ́ ọgọ́rùún mẹ́fà ati mọ́kàndínlọ́gbọ̀n. Àwọn tí wọn kò tíì gbádùn tí wọn kò sì kú jẹ́ ọgọ́rùún márùún àti ọgọ́sàán ó dín mẹ́jọ. Ní ìparí oṣù Kẹfà.[20]
Àwọn ìgbésẹ̀ ìdènà àjakálẹ̀ àrùn náà
àtúnṣeLáti inú oṣù kẹ́ta, gbogbo àyẹ̀wò àrùn tí.wọ́n ti ṣe fún àwọn ènìyàn ni ó jẹ́ wípé wọn kò pe ìjọba ilẹ̀ òkèrè dá si rárá. Wọ́n ń tọ́jú àwọn àyẹ̀wò wọn sí inú láàbù (Laboratório de Virologia de Cabo Verde), ní Ìlú Praia.[21] Ní ọjọ́ kẹtàdínlógún olórí aláṣẹ ilẹ̀ Cape Verde ọ̀gbẹ́ni José Ulisses Correia e Silva pàṣẹ pékí wọ́n ti gbogbo ẹnu ìloro tí ó wọ orílẹ̀-èdè náà pa tó fi mọ́ ẹnu ibodè ti orí omi léte ati dẹ́kun ìtànkálẹ̀ àjàkélẹ̀ àrùn COVID-9 láti àwọn orílẹ̀-èdè tí àrùn náà ti rọ́wọ́ họrí gidi bíi: orílẹ̀-èdè Brazil orílẹ̀-èdè USA, orílẹ̀-èdè Senegal, orílẹ̀-èdè Portugal, orílẹ̀-èdè Nàìjíríà àti àwọn orílẹ̀-èdè Europe káàkiri. Amọ́ ṣá, wọ́n fàyè gba ọkọ̀ òfurufú tí ó bá kó ẹrù nìkan kí ó palẹ̀ sí pápákọ̀ òfurufú wọn. Bákan náà ni wọ́ tún fàyè gba àwọn ọmọ.orílẹ̀-èdè mìíràn tí wọ́n bá nífẹ́ láti padà sí orílẹ̀-èdè wọn. Wọ́n gbé ìgbésẹ̀ yí fún odidi ọ̀sẹ̀ mẹ́ta. [22][23][24] [25] [26] [27] Ìjọba orílẹ̀-èdè Cape Verde fún ìgbà akọ́kọ́ kéde kónílé-ó-gbélé tí ó jẹ́ ti pàjáwìrì ní ọjọ́ kejìdínlógún oṣù kẹ́ta ọdún 2020, léte àti mú àdínkù bá ìfara-kínra àwọn ènìyàn tí óń mú àrùn náà pọ̀ si. Ìgbésẹ̀ yí ṣe akóbá lọ́pọ̀lọpọ̀ fún okòwò àwọn ènìyàn ati ti ìjọba fúnra rẹ̀.[28][29]
Ẹ tún lè wo
àtúnṣeÀwọn ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ "COVID 19 – Corona Virus" (in Èdè Pọtogí). Retrieved 2020-05-23.
- ↑ "COVID 19 – Corona Virus" (in Èdè Pọtogí). Retrieved 2020-07-22.
- ↑ "Cape Verde reports first confirmed case of COVID-19 - Xinhua | English.news.cn". www.xinhuanet.com. Archived from the original on 2020-03-22. Retrieved 2020-05-26.
- ↑ Elsevier. "Novel Coronavirus Information Center". Elsevier Connect. Archived from the original on 30 January 2020. Retrieved 15 March 2020. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ Reynolds, Matt (4 March 2020). "What is coronavirus and how close is it to becoming a pandemic?". Wired UK. ISSN 1357-0978. https://www.wired.co.uk/article/china-coronavirus.
- ↑ 6.0 6.1 "Crunching the numbers for coronavirus". Imperial News. Archived from the original on 19 March 2020. Retrieved 15 March 2020. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ "High consequence infectious diseases (HCID); Guidance and information about high consequence infectious diseases and their management in England". GOV.UK (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Archived from the original on 3 March 2020. Retrieved 17 March 2020. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ "World Federation Of Societies of Anaesthesiologists – Coronavirus". www.wfsahq.org. Archived from the original on 12 March 2020. Retrieved 15 March 2020. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ Future scenarios of the healthcare burden of COVID-19 in low- or middle-income countries, MRC Centre for Global Infectious Disease Analysis at Imperial College London.
- ↑ "Cape Verde registers an Adverse Analytical Finding of First COVID-19" (in English). 20 March 2020. https://www.insp.gov.cv/index.php/noticias/400-cabo-verde-regista-um-primeiro-caso-positivo-de-covid-19.
- ↑ "Coronavírus: Inglês de 62 anos é o primeiro caso confirmado em Cabo Verde" (in Portuguese). 20 March 2020. https://www.publico.pt/2020/03/20/mundo/noticia/coronavirus-ingles-62-anos-caso-confirmado-cabo-verde-1908619.
- ↑ SAPO. "Covid-19: Há mais dois casos confirmados na Boa Vista. Suspeito de São Vicente é negativo". SAPO Lifestyle (in Èdè Pọtogí). Archived from the original on 27 March 2020. Retrieved 21 March 2020.
- ↑ "COVID-19: confirmed the first death from coronavirus in Cape Verde". insp.gov.cv (in English). 24 March 2020. Retrieved 25 March 2020.
- ↑ "Confirmado primeiro caso de COVID-19 na Praia". expressodasilhas.cv (in Èdè Pọtogí). Retrieved 25 March 2020.
- ↑ "Cape Verde registers the fourth positive case COVID-19". insp.gov.cv (in English). 25 March 2020. Retrieved 27 March 2020.
- ↑ "Teste à esposa do primeiro caso da Praia dá positivo (em actualização)". expressodasilhas.cv (in Èdè Pọtogí). Retrieved 26 March 2020.
- ↑ "Coronavirus disease (COVID-19) situation report 72" (PDF). World Health Organization. 1 April 2020. p. 8. Retrieved 20 July 2020.
- ↑ "Coronavirus disease (COVID-19) situation report 102" (PDF). World Health Organization. 1 May 2020. p. 6. Retrieved 20 July 2020.
- ↑ "Coronavirus disease (COVID-19) situation report 133" (PDF). World Health Organization. 1 June 2020. p. 7. Retrieved 20 July 2020.
- ↑ "Coronavirus disease (COVID-19) situation report 163" (PDF). World Health Organization. 1 July 2020. p. 7. Retrieved 20 July 2020.
- ↑ "Covid-19: Laboratório de Cabo Verde com capacidade para 300 testes diários". A Semana (in Portuguese). 16 March 2020. Retrieved 20 March 2020.
- ↑ Àdàkọ:Cite url
- ↑ "COVID19: Governo declara situação de contingência a nível da Proteção Civil" (in Portuguese). Governo de Cabo Verde. 17 March 2020. Retrieved 20 March 2020.
- ↑ "Governo declara situação de contingência, a nível de Proteção Civil, por causa do Covid-19". TCV (in Portuguese). 17 March 2020. Archived from the original on 20 March 2020. Retrieved 20 March 2020.
- ↑ "Check out the new measures announced by the government in the prevention of COVID-19" (in English). 18 March 2020. https://www.insp.gov.cv/index.php/component/content/article/105-slideshow/399-confira-as-novas-medidas-anunciadas-pelo-governo-no-ambito-da-prevencao-do-covid-19?Itemid=437.
- ↑ ""We raise the contingency level of Civil Protection to disaster risk" - Ulisses Correia e Silva" (in English). 27 March 2020. https://www.insp.gov.cv/index.php/noticias/404-elevamos-o-nivel-de-contingencia-da-proteccao-civil-a-situacao-de-risco-de-calamidade-ulisses-correia-e-silva.
- ↑ "Corona Virus: Flights suspensions". Cabo Verde Airlines. 17 March 2020. Archived from the original on 20 March 2020. Retrieved 20 March 2020.
- ↑ "Declaration of a state of emergency by the President of the Republic of Cape Verde" (in English). 28 March 2020. https://www.insp.gov.cv/index.php/component/content/article/105-slideshow/406-declaracao-de-estado-de-emergencia-pelo-presidente-da-republica-de-cabo-verde?Itemid=437.
- ↑ Boletim Oficial da República de Cabo Verde — Suplemento, I Série, Número 38
Àwọn Ìtàkùn ìjásóde
àtúnṣe- Instituto Nacional de Saúde Pública - Cape Verde's Public Health National Institute
- COVID 19 — Corona Vírus - Official site about COVID-19 in Cape Verde