Àjàkálẹ̀ Àrùn COVID-19 ní Orilẹ̀-èdè Chad
Àjàkálẹ̀ Àrùn COVID-19 dé Orilẹ̀-èdè Chad ní inú oṣù Kẹ́ta ọdún 2020.
Àjàkálẹ̀ Àrùn COVID-19 ní Orilẹ̀-èdè Chad | |||||||||
---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|
| |||||||||
Àrùn | COVID-19 | ||||||||
Irú kòkòrò èràn | SARS-CoV-2 | ||||||||
Ibi | Chad | ||||||||
Index case | N'Djamena | ||||||||
Arrival date | 19 March 2020 (4 years, 8 months and 6 days) | ||||||||
Gbogbo iye àwọn ẹ̀sùn | 915 (as of 23 July)[1] | ||||||||
Active cases | 35 (as of 23 July)[1] | ||||||||
Iye àwọn tí ara wọn ti yá | 805 (as of 23 July)[1] | ||||||||
Iye àwọn aláìsí | 75 (as of 23 July)[1] |
Bí ó ṣe bẹ̀rẹ̀
àtúnṣeNí ọjọ́ Kejìlá oṣù Kíní ọdún 2020, Àjọ ìṣọ̀kan tí ó ń rí sí ìlera ní àgbáyé fìdí àrùn Kòrónà tí a tún ń pè ní Kofid-19 ní orílẹ̀-m àgbáyé ní ọjọ́ Kejìlá oṣù Kínní ní ọdún 2020. Tí wọ́n sì fìdí rẹ̀ múlẹ̀ wípé àrùn yí bẹ̀rẹ̀ ní ìlú kan tí wọ́n ń pè ní Wuhan, ní ẹkùn Hubei ní orílẹ̀-èdè China. Àmọ́ ó tó ọjọ́ Kẹtalélọ́gbọ̀n oṣù Kejìlá ọdún 2019 kí wọ́n tó fi tó àjọ ìṣòkan àgbáyé létí.[2][3]
Wón tún fìdí rẹ̀ múlẹ̀ siwájú si wípé bí àrùn yí bá ti mú ènìyàn, oun ni ó ń fa ìfúnpinpin ní ní inú káà ọ̀fun ati àyà, tí ó sì ma ń fa kàtá tàbí kí ènìyàn ó ma wú ikọ́ tàbí sín léra léra. Iye ìjàmbá tí àrùn Kòrónà ti fà lágbáyé kéré sí iye ìjàmbá tí àìsàn àrùn ọ̀fun SARS ti fà láti ọdún 2003. Àmọ́ iye àwọn ènìyàn tí wọ́n tó àrùn Kòrónà látàrí ríràn tí ó ń ràn kálẹ̀ ti.pọ̀ ju ti SARS lọ, bí ó ti lẹ̀ jẹ́ wípé ìtànkálé àrùn COVID-19 ń gbópọn si lójojúmọ́ tí ó sì ti ṣekú pa ọ̀pọ̀lọpò ènìyàn lágbáyé. [4][5][6][4] [7]
Bí ó ṣe ń ṣẹlẹ̀ láw9n àsìkò kọ̀ọ̀kan
àtúnṣeOṣù Kẹ́ta ọdún 2020
àtúnṣeNí ọjọ́ Kọkàndínlógún oṣù Kẹ́ta, ìjọba orílẹ̀-èdè Chad fìdí ìṣẹ̀lẹ̀ àrùn Kòrónà àkọ́kọ́ múlẹ̀, tí ẹni akọ́kọ́ náà sì jẹ́ èrò 9kọ̀ Morocco tí ó sá kúrò ní Ìlú Douala.[8]
Ní ọjọ́ kẹrìndínlọ́gbọ̀n oṣù Kẹ́ta, wọ́n ti fìdí ìṣẹ̀lẹ̀ àrùn Kòrónà tí ó tó mẹ́ta múlẹ̀ ní orílẹ̀-èdè Chad. Ẹni akọ́kọ́ nínú àwọn aláìsàn náà jẹ́ ọmọ orílé-èdè Chad tí ọjọ́ orí rẹ̀ kò ju méjìdínláàdọ́ta lọ. Ẹnìkejì ni ọmọ orílẹ̀-èdè Cameroon tí ọjọ́ orí rẹ̀ kò ju ọdún márùnléláàdọ́ta lọ tí ó jẹ́ èrò ọkọ̀ òfurufú Ethiopia tí ó ń darí bọ̀ láti Ìlú Dubai, Brussels àti Addis Ababa. [9]
Ní ọgbọ̀njọ́ oṣù Mẹ́ta, wọ́n tún fìdí àwọn ènìyàn tí ó ti kó àrùn Kòrónà méjì míràn múlẹ̀. Ẹni akọ́kọ́ ni ọmọ.orílẹ̀-èdè Chad rí dé láti Ìlú Douala , rí ẹnìkejì sì jẹ́ ọmọ Oríṣi Switzerland tí ó ń bọ̀ láti Ìlú Brussels.[10] Akọsílẹ̀ méje péré ni wọ́n rí ní inú oṣù Kẹ́ta, nígbà tí wọn kò pàdánù ẹnìkọkan, bẹ́ẹ̀, kò sí ẹnikẹ́ni tí ara rẹ̀ yá tí ó sì padà sílé rẹ̀. [11]
Oṣù Kẹ́rin ọdún 2020
àtúnṣeNí ọjọ́ kejì oṣù Kẹ́rin, wọ́n tún ní akọsílẹ̀ kan tí ó jẹ́ ọmọ orílẹ̀-èdè Chad tí ń bò láti Ìlú Dubai ṣùgbọ́n tí ó gba Ìlú Àbújá ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà kọjá.[12] Ní ọjọ́ Kẹta oṣù Kẹ́ta, ẹlòmíràn náà tún kó àrùn yí wọ orílẹ̀-èdè Chad ẹni tí ó jẹ́ ọmọ orílẹ̀-èdè Faranse tí ó ń bọ̀ láti Ìlú Brussels, àmọ́ tí ó gba Ìlú Paris kọjá[13] Orílẹ̀-èdè Chad tún ní akọsílẹ̀ tuntun tí ó jẹ́ ti abẹ́lé. Ọmọ.orílẹ̀-èdè Chad kan tí ó jẹ́ ẹni ọdún mọ́kànlélọ́gbọ̀n tí ó ti ní ìfara-kínra pẹ́lú ọmọ.orílẹ̀-èdè.Chad míràn.tí óun ti ní kòkòrò àrùn Kòrónà tẹ́lẹ̀.[14] Ní ọjw Kesàán oṣù Kẹ́ta yí kan náà, àwọn òṣìṣẹ́ ìlera fi ẹnìkan tí ó jẹ́ ọmọ orílẹ̀-èdè Chad tí ó ń bọ̀ láti orílẹ̀-èdè Pakistan, tí ó gba orílẹ̀-èdè Cameroon kọjá kí ó tó dé Ìlú kan tí wọ́n ń pè ní N'Djamena. Ìlú Abéché ni wọ́n ti rọ́wọ́ to nígba tí wọ́n ṣàyẹ̀wò ẹ̀jẹ̀ rẹ̀ ní ọjọ́ Kẹrin oṣù Kẹ́ta tí èsì àyẹ̀wò rẹ̀ sì fìdí rẹ̀ múlẹ̀ wípé ó ti ní kòkòrò àrùn Kòrónà lẹ́yìn ọjọ́ kẹrin tí wọ́n ti fi sí iyàrá àdágbé.[15]
During April there were 66 new cases, bringing the total number of confirmed cases to 73. Two deaths were reported on 28 April and three more on 30 April, bringing the total death toll to five. 33 patients recovered, leaving 35 active cases at the end of the month.[16]
Oṣù Karùún ọdún 2020
àtúnṣeIye àwọn ènìyàn tí ó kó àrùn yí ní inú oṣù yí jẹ́ 705 lápapọ̀, tí iye ènìyàn tí gbẹ́mímì jẹ́ 65, nígbà tí iye àwọn tí wọ́n ìmúláradá jẹ́ 458.[17]
Oṣù Kẹfa ọdún 2020
àtúnṣeWọ́n ṣàwárí iye ènìyàn tí ó tó méjì dín lọ́gọ́sàán tí wọ́n ní arùn Kòrónà nínú oṣù yí tí ó sì mú kí iye àwọn tí wọ́n ní àìsàn yí.láti ìbẹ̀rẹ̀ oṣù Kẹ́ta ó jẹ́ 866, nígbà tí iye àwọn tí wọ́n jẹ́ aláìsí lápapọ̀ jẹ́ 74, tí àwọn 781 sì gba ìwòsàn padà sí Ilé wọn láyọ̀ àti àlááfià. Iye àwọn tí wọn kò tíì rí ìwòsàn gbà tí wọn kò sì kú jẹ́ mọ́kànlá péré ní ìparí oṣù Kẹfà ọdún 2020.[18]
Àwọn ìgbésẹ̀ tí Ìjọba ilẹ̀ Chad gbé
àtúnṣeLáti dẹ́kun ìtànkálẹ̀ àrùn yí siwájú si, wọ́n fagilé gbogbo ìgbòkègbodò ìrìnà ọkọ̀ òfurufú pátá, yàtọ̀ sí èyí tí ó bá kó ẹrù nìkan.[19][20]
Ẹ tún lè wo
àtúnṣeÀwọn Ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ 1.0 1.1 1.2 1.3 "Coronavirus in Africa tracker". bbc.co.uk. Retrieved 23 July 2020. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ Elsevier. "Novel Coronavirus Information Center". Elsevier Connect. Archived from the original on 30 January 2020. Retrieved 15 March 2020. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ Reynolds, Matt (4 March 2020). "What is coronavirus and how close is it to becoming a pandemic?". Wired UK. ISSN 1357-0978. https://www.wired.co.uk/article/china-coronavirus.
- ↑ 4.0 4.1 "Crunching the numbers for coronavirus". Imperial News. Archived from the original on 19 March 2020. Retrieved 15 March 2020. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ "High consequence infectious diseases (HCID); Guidance and information about high consequence infectious diseases and their management in England". GOV.UK (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Archived from the original on 3 March 2020. Retrieved 17 March 2020. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ "World Federation Of Societies of Anaesthesiologists – Coronavirus". www.wfsahq.org. Archived from the original on 12 March 2020. Retrieved 15 March 2020. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ Future scenarios of the healthcare burden of COVID-19 in low- or middle-income countries, MRC Centre for Global Infectious Disease Analysis at Imperial College London.
- ↑ "Chad confirms first case of coronavirus: government statement". Reuters. 19 March 2020. https://www.reuters.com/article/us-health-coronavirus-chad/chad-confirms-first-case-of-coronavirus-government-statement-idUSKBN2162LO. Retrieved 19 March 2020.
- ↑ Alwihda, Info. "Coronavirus : Le Tchad annonce deux nouveaux cas". Alwihda Info - Actualités TCHAD, Afrique, International (in Èdè Faransé). Retrieved 2020-04-01.
- ↑ Alwihda, Info. "Tchad - COVID-19 : un tchadien et un suisse testés positifs". Alwihda Info - Actualités TCHAD, Afrique, International (in Èdè Faransé). Retrieved 2020-04-09.
- ↑ "Coronavirus disease (COVID-19) situation report 72" (PDF). World Health Organization. 1 April 2020. p. 8. Retrieved 2020-07-16.
- ↑ "Coronavirus au Tchad : voici comment l'équipe du 1313 a pu découvrir le 8ème cas". Tchadinfos.com (in Èdè Faransé). 2020-04-03. Retrieved 2020-04-09.
- ↑ Alwihda, Info. "Tchad : un 9ème cas de COVID-19 détecté". Alwihda Info - Actualités TCHAD, Afrique, International (in Èdè Faransé). Retrieved 2020-04-09.
- ↑ "Covid-19 : les autorités sanitaires confirment le 10e cas". Journal du Tchad (in Èdè Faransé). Archived from the original on 2020-04-11. Retrieved 2020-04-11.
- ↑ "Coronavirus : le Tchad annonce son 11e cas, un marabout venu du Pakistan". Tchadinfos.com (in Èdè Faransé). 2020-04-09. Retrieved 2020-04-11.
- ↑ "Coronavirus disease (COVID-19) situation report 103" (PDF). World Health Organization. 2020-05-02. p. 5. Retrieved 2020-07-16.
- ↑ "Coronavirus disease (COVID-19) 133" (PDF). World Health Organization. 1 June 2020. p. 7. Retrieved 16 July 2020.
- ↑ "Coronavirus disease (COVID-19) situation report 163" (1 July 2020). World Health Organization. p. 7. Retrieved 16 July 2020.
- ↑ "Coronavirus-free Chad shuts borders, airports". The Cable (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2020-03-17. Archived from the original on 17 March 2020. Retrieved 2020-03-17. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ "Chad to close airports over coronavirus fears". Medical Xpress (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2020-03-16. Archived from the original on 17 March 2020. Retrieved 2020-03-17. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help)
Àwọn Ìtàkùn Ìjásóde
àtúnṣe- Media related to COVID-19 pandemic in Chad at Wikimedia Commons