Pakístàn

orílẹ̀-èdè ní Ásíà
(Àtúnjúwe láti Pakistan)

Pakístàn (/ˈpækɪˌstæn/  (Speaker Icon.svg listen) tabi /ˌpɑkɨˈstɑːn/  (Speaker Icon.svg listen); Urdu: پاکِستان) (Pípè ní Urdu: [paːkɪsˈtaːn]  ( ẹ tẹ́tí gbọ́)), lonibise bi Órílẹ̀-èdè Olómìnira Onímàle ilẹ̀ Pakístàn (Urdu: اسلامی جمہوریہ پاکِستان) je orile-ede kan ni Guusu Asia. O ni ile etiomi to to 1,046-kilometre (650 mi) leba Omiokun Arabia ati Omiala Oman ni guusu, be sini o ni bode mo Afghanistan ati Iran ni iwoorun, India ni ilaorun ati Shaina ni ookan ni ariwailaorun.[7] Bakanna Tajikistan na sunmo Pakistan sugbon aaye Odede Wakhan tinrin pin won soto. Letanletan o budo si ipo larin awon agbegbe pataki Guusu Asia, Alaarin Asia ati Ibiarin Ilaorun.[8]

Órílẹ̀-èdè Olómìnira Onímàle ilẹ̀ Pakístàn
Islamic Republic of Pakistan
اسلامی جمہوریہ پاکستان

Islāmī Jumhūrī-ye Pākistān

Àsìá Ẹ́mblẹ́m Orílẹ̀-ìjọba
MottoUnity, Discipline, Faith
(Urdu: اتحاد، تنظيم، يقين مُحکم)
Ittehad, Tanzeem, Yaqeen-e-Muhkam
Orin-ìyìn orílẹ̀-èdèQaumī Tarāna
OlúìlúIslamabad
33°40′N 73°10′E / 33.667°N 73.167°E / 33.667; 73.167
ilú títóbijùlọ Karachi
Èdè àlòṣiṣẹ́ Urdu (National)
English
Àwọn èdè dídámọ̀ níbẹ̀ Balochi, Pashto, Punjabi, Saraiki, Sindhi [1]
Orúkọ aráàlú Ará Pakistan
Ìjọba Federal Parliamentary republic
 -  Founder Muhammad Ali Jinnah
 -  President Mamnoon Hussain (PML-N)
 -  Prime Minister Mian Nawaz Sharif (PML-N)
 -  Chief Justice Iftikhar Chaudhry
 -  Chair of Senate Farooq Naek (PPP)
Aṣòfin Majlis-e-Shoora
 -  Ilé Aṣòfin Àgbà Senate
 -  Ilé Aṣòfin Kéreré National Assembly
Formation
 -  Pakistan Declaration January 1933 
 -  Pakistan Resolution 23 March 1940 
 -  Independence from the United Kingdom 
 -  Declared 14 August 1947 
 -  Islamic Republic 23 March 1956 
Ààlà
 -  Àpapọ̀ iye ààlà 796,095 km2 (36th)
307,374 sq mi 
 -  Omi (%) 3.1
Alábùgbé
 -  Ìdíye 2020 170.6 million[2] (6th)
 -  1998 census 132,352,279[3] 
 -  Ìṣúpọ̀ olùgbé 214.3/km2 (55th)
555/sq mi
GIO (PPP) ìdíye 2010
 -  Iye lápapọ̀ $451.972 billion[4] 
 -  Ti ẹnikọ̀ọ̀kan $2,713[4] 
GIO (onípípè) Ìdíye 2010
 -  Àpapọ̀ iye $177.901 billion[4] 
 -  Ti ẹnikọ̀ọ̀kan $1,067[4] 
Gini (2005) 31.2 (medium
HDI (2007) 0.572[5] (medium) (141st)
Owóníná Pakistani Rupee (Rs.) (PKR)
Àkókò ilẹ̀àmùrè PST (UTC+5)
 -  Summer (DST) PDT (UTC+6)
Ìwakọ̀ ní ọwọ́ left[6]
Àmìọ̀rọ̀ Internet .pk
Àmìọ̀rọ̀o tẹlifóònù 92


ItokasiÀtúnṣe

  1. "Population by Mother Tongue" (PDF). Population Census Organization of Pakistan. Retrieved 22 September 2010. 
  2. "Official Pakistani Population clock". Ministry of Economic Affairs and Statistics. Retrieved 17 January 2010. 
  3. "Area, Population, Density and Urban/Rural Proportion by Administrative Units". Population Census Organization, Government of Pakistan. Retrieved 13 February 2008. 
  4. 4.0 4.1 4.2 4.3 "Pakistan". International Monetary Fund. Retrieved 21 April 2010. 
  5. "Human Development Report 2009. Human development index trends: Table G" (PDF). The United Nations. Retrieved 5 October 2009. 
  6. Loureiro, Miguel (28 July 2005). "Driving—the good, the bad and the ugly". Daily Times (Pakistan). Archived from the original on 30 May 2012. https://archive.is/3TqH. Retrieved 10 January 2010. 
  7. Agbegbe Kashmir dija larin Pakistan ati India. Pakistan unpe apa Kashmir ti India samojuto bi Kashmir ti India gbowole.
  8. Yasmeen (2007), p.3.