Àjàkálẹ̀ àrùn Covid-19 ní Puntland

Àjàkálẹ̀ àrùn Covid-19 kọ́kọ́ rápálá wọ Puntland, tí ó jẹ́ Ìpínlẹ̀ kan ní orílẹ̀-èdè Somalia, ṣùgbọ́n tí wọ́n dá dúró lọ́wọ́ ara wọn yàtọ̀ sí Somalia gẹ́gẹ́ bí àwọn àjọ àgbáyé ṣe gbà wọ́n .[1]

Àjàkálẹ̀ àrùn Covid-19 ní Puntland
ÀrùnCOVID-19
Irú kòkòrò èrànSARS-CoV-2
IbiPuntland

Àpapọ̀ iye àwọn tí wọ́n ní àrùn Covid-19 Puntland lọ́jọ́ kejì Osun karùn-ún ọdún 2020 jẹ́ mẹ́jọ, tí ènìyàn kan péré sìn kú, bí ó tilẹ̀ jẹ́ pé àwọn aláṣẹ ìjọba Puntland gbàgbọ́ iye àwọn iye àwọn tí wọ́n ní àrùn náà ju báyìí lọ.[2][3]Títí dọjọ́ kejì oṣù karùn-ún ọdún 2020, Puntland jẹ́ ẹkùn ìṣẹ̀jọba kan ní orílẹ̀ èdè Somalia tí wọ́n wà ní ìpò kẹta nínú àwọn ẹkùn ìṣẹ̀jọba tí àrùn Covid-19 tí pọ̀jù, lẹ́yìn Banaadir àti ilẹ̀ Olómìnira Somaliland [1]

Bí àrùn náà ṣe ń jàkálẹ̀ láti ìgbà dé ìgbà àtúnṣe

Oṣù kẹta ọdún 2020 àtúnṣe

Àwọn aláṣẹ ìjọba Puntland kọ́kọ́ kọ̀ jálẹ̀ láti tí àwọn ilé ìjọsìn àwọn ẹlẹ́sìn Mùsùlùmí pa nígbà tí àrùn Covid-19 ṣẹ́yọ ní àwọn ẹkùn ìṣèjọba orílẹ̀ èdè Somalia lóṣù kẹta ọdún 2020. [4]

Oṣù karùn-ún ọdún 2020 àtúnṣe

Ní oṣù karùn-ún ọdún 2020, ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn mínísítà àti àwọn olùgbaninímọ̀ràn tí Ààrẹ Puntland, Said Abdullahi Dani ni èsì àyẹ̀wò ti fihàn pé wọ́n ti kó àrùn Covid-19. [1] Puntland Health Minister Jama Farah Hassan stated that two Puntland government ministers had tested positive by May 8, 2020.[3][5]

Lọ́jọ́ kẹfà oṣù karùn-ún ọdún 2020 ní Mínísítà ètò ọ̀rọ̀-ajé tí àgbègbè ìṣẹ̀jọba Puntland, Abdullahi Abdi Hirsi kọ́kọ́ kéde pé òun ní ojú dídunni, èyí tí ó ṣeé ṣe kí ó jẹ́ ọ̀kan lára àmìn àrùn Covid-19. [6] He sought treatment and was diagnosed with the COVID-19 on May 9, 2020.[6] Lọ́jọ́ díẹ̀ sẹ́yìn, Hirsi ti ṣe àbẹ̀wò sí àgbègbè kan ní Qardho, tí ẹ̀kún omi jà lásìkò náà, ó ní ìgbàgbọ́ pé ibẹ̀ ni òun ti kó àrùn ẹ̀rànkòrónà. [6]

Lọ́jọ́ karùndínlọ́gbọ̀n oṣù karùn-ún ọdún 2020, ilé-isẹ́ ìjọba lórí ètò àgbẹ̀ kéde ikú mínísítà ilé-isẹ́ náà, Ismail Gamadiid pé ó pàpòdà láti owó àrùn Covid-19.[1] Gamadiid had contracted the coronavirus in Puntland, but had been transferred to a hospital in Mogadishu for treatment for several weeks.[1][7]

Ẹ yẹ̀yí wò àtúnṣe

Àwọn Ìtọ́kasí àtúnṣe

  1. 1.0 1.1 1.2 1.3 1.4 "Somalia: Puntland's Minister for Agriculture Dies of Coronavirus in Mogadishu". Menafn. 2020-05-25. Archived from the original on 2020-06-07. https://web.archive.org/web/20200607023919/https://menafn.com/1100221033/Somalia-Puntlands-Minister-for-Agriculture-Dies-of-Coronavirus-in-Mogadishu. Retrieved 2020-06-07. 
  2. "Puntland and COVID-19: Local Responses and Economic Impact". The Conflict Research Programme at the London School of Economics and Political Science. 2020-05-05. Archived from the original on 2020-06-07. https://web.archive.org/web/20200607033735/https://blogs.lse.ac.uk/crp/2020/05/05/puntland-and-covid-19-local-responses-and-economic-impact/. Retrieved 2020-06-07. 
  3. 3.0 3.1 "Somalia: Puntland ministers contract Covid-19-health minister". Somaliland Standard. 2020-05-08. Archived from the original on 2020-06-03. https://web.archive.org/web/20200603111901/https://somalilandstandard.com/somalia-puntland-ministers-contract-covid-19-health-minister/. Retrieved 2020-06-07. 
  4. "Coronavirus: Muxuu yahay heshiiska ay Culimada iyo maamulka Puntland ka gaareen xiridda Masaajidyada?". BBC Somali Service. 2020-03-24. Archived from the original on 2020-06-07. https://web.archive.org/web/20200607033523/https://www.bbc.com/somali/war-52020191. Retrieved 2020-06-07. 
  5. "Puntland state ministers test positive for Covid-19". Somali Affairs News. 2020-05-08. Archived from the original on 2020-06-04. https://web.archive.org/web/20200604144000/https://www.somaliaffairs.com/news/puntland-state-ministers-test-positive-for-covid-19/. Retrieved 2020-06-07. 
  6. 6.0 6.1 6.2 "Wasiirka Puntland ee coronavirus laga helay oo BBC-da la hadlay". BBC Somali Service. 2020-05-11. Archived from the original on 2020-06-07. https://web.archive.org/web/20200607032937/https://www.bbc.com/somali/war-52619528. Retrieved 2020-06-07. 
  7. "Somalia: Puntland Minister Succumbs to COVID-19". Dalsan Radio (AllAfrica.com). 2020-05-25. Archived from the original on 2020-06-06. https://web.archive.org/web/20200604214939/https://allafrica.com/stories/202005260181.html. Retrieved 2020-06-07.