Àjàkálẹ̀ àrùn Covid-19 lórílẹ̀-èdè Olómìnira Benin

Àjàkálẹ̀ àrùn Ẹ̀rànkòrónà-19 tí gbogbo ènìyàn mọ̀ sí COVID-19 kọ́kọ́ bẹ́ sílẹ̀ ní Orílẹ̀-èdè Olómìnira Benin ní oṣù kẹta ọdún 2020.

Àjàkálẹ̀ àrùn Covid-19 lórílẹ̀-èdè Olómìnira Benin
Arákùnrin ará Benin kan tí ó wọ ìbòjú ìdáàbòbò fún àjàkálẹ̀ àrùn Covid-19 lórílẹ̀-èdè Olómìnira Benin.
ÀrùnCOVID-19
Irú kòkòrò èrànSARS-CoV-2
IbiOrílẹ̀-èdè Olómìnira Benin
Ìjásílẹ̀ àkọ́kọ́Wuhan, China
Index casePorto-Novo
Arrival dateọjọ́ kẹrìndínlógún ní oṣù kẹta ọdún 2020. 2020
(3 years, 11 months, 2 weeks and 2 days)
Gbogbo iye àwọn ẹ̀sùn1,124 (as of 27 June 2020)[1]
Active cases815 (títí di ọjọ́ kẹtàdínlọ́gbọ̀n oṣù kẹfà ọdún 2020)
Iye àwọn tí ara wọn ti yá295 ( títí di ọjọ́ kẹtàdínlọ́gbọ̀n oṣù kẹfà ọdún 2020)[1]
Iye àwọn aláìsí
14 (títí di ọjọ́ kẹtàdínlọ́gbọ̀n oṣù kẹfà ọdún 2020)[1]
Official website
https://sante.gouv.bj/COVID19-TOUT-SAVOIR-SUR-LA-GESTION-DE-LA-PANDEMIE-AU-BENIN

Bí ó ṣe bẹ̀rẹ̀ àtúnṣe

Lọ́jọ́ Kejìlá oṣù kìíní ọdún 2020 ni àjọ elétò ìlera àgbáyé, World Health Organization (WHO) jẹ́rìí pé ẹ̀rànkòrónà, Covid-19, ni ó ń fa àìsàn èémí láàárín àwọn ènìyàn kan lágbègbè Wuhan,ní Ìpínlẹ̀ Hubei, lórílẹ̀-èdè China, èyí tí wọ́n jábọ̀ rẹ̀ fún àjọ WHO lọ́jọ́ kokànlélọ́gbọ̀n oṣù Kejìlá ọdún 2019.[2][3]

Iye ìjàm̀bá ikú àrùn Covid-19 kéré sí ti àrùn SARS, Severe acute respiratory syndrome tó bẹ́ sílẹ̀ lọ́dún 2003,[4][5] ṣùgbọ́n jíjàkálẹ̀ àrùn náà lágbára ju SARS lọ, pàápàá jù lọ iye àwọn ènìyàn tí àrùn náà ń pa lápapọ̀.[6][4]

Ìbúrẹ́kẹ́ àrùn náà láti ìgbà dé ìgbà àtúnṣe

Àdàkọ:COVID-19 pandemic data/Benin medical cases chart Ẹni àkọ́kọ́ tí wọ́n kéde rẹ̀ pé ó lùgbàdì àrùn náà lórílẹ̀ èdè Olómìnira Benin wáyé ní olú-ìlú orílẹ̀-èdè náà, Port-Novo, lọ́jọ́ kẹrìndínlógún oṣù kẹta ọdún 2020,On.[7] Lọ́jọ́ kẹta sì ara wọn ní wọ́n, ni wọ́n kéde ènìyàn kejì tó ní àrùn náà. Lẹ́sẹ̀kẹsẹ̀ ni orílẹ̀-èdè kéde ìdádúró ìrìnkèrindò ọkọ̀ láti orílẹ̀ èdè mìíràn wá sí orílẹ̀ èdè náà, bákan náà wọ́n yàn ìdágbélé tipátipá fún gbogbo àwọn àrè tàbí arìnrìn-àjò tí wọ́n bá wọ orílẹ̀-èdè náà gba òfurufú. Kódà, wọ́n gba àwọn olùgbé orílẹ̀ èdè Benin ní ìmọ̀ràn láti máa wọ ìbòjú, kí Wọ́n sìn ṣé ara wọn mọ́lé àyàfi bí ó bá pọn dandan láti jáde.[8]

Àwọn Ìtọ́kasí àtúnṣe

  1. 1.0 1.1 1.2 "Coronavirus (Covid-19)". Gouvernement de la République du Bénin (in Èdè Faransé). Retrieved 2020-06-27. 
  2. Elsevier. "Novel Coronavirus Information Center". Elsevier Connect. Archived from the original on 30 January 2020. Retrieved 15 March 2020.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  3. Reynolds, Matt (4 March 2020). "What is coronavirus and how close is it to becoming a pandemic?". Wired UK. ISSN 1357-0978. https://www.wired.co.uk/article/china-coronavirus. 
  4. 4.0 4.1 "Crunching the numbers for coronavirus". Imperial News. Archived from the original on 19 March 2020. Retrieved 15 March 2020.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  5. "High consequence infectious diseases (HCID); Guidance and information about high consequence infectious diseases and their management in England". GOV.UK (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Archived from the original on 3 March 2020. Retrieved 17 March 2020.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  6. "World Federation Of Societies of Anaesthesiologists – Coronavirus". www.wfsahq.org. Archived from the original on 12 March 2020. Retrieved 15 March 2020.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  7. "Somalia, Liberia, Benin and Tanzania confirm first coronavirus cases". Reuters (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2020-03-16. Retrieved 2020-03-16. 
  8. "Coronavirus: Benin records second positive case". Panapress (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2020-03-19. Retrieved 2020-03-19.