Àjọ Alákòóso fún Rélùwéè ilẹ̀ China

Àdàkọ:Recentism

Ministry of Railways of the
People's Republic of China
中华人民共和国铁道部
Zhōnghuá Rénmín Gònghéguó Tiědàobù
Agency overview
Dissolved March 2013
Jurisdiction China
Headquarters Beijing
Minister responsible Sheng Guangzu
Parent agency State Council


Àjọ Alákòóso fún Rélùwéè ilẹ̀ China (MOR) ni ilé-iṣẹ́ tí ó wà ní abẹ́ State Council of the People's Republic of China amọ́ tí kò ṣiṣẹ́ mọ́. Ẹni tí ó jẹ́ Mínísítà kẹyìn fún àjọ yí ni Sheng Guangzu.[1]

Ojúṣe àjọ yí ni kí wọ́n ṣe àbójútó lílọ bíbọ̀ èrò ọkọ̀ láì sí ìdíwọ́ kan kan, ṣiṣẹ́ ètò ati ìgbòkègbodò ọkọ̀ ojú irin, mímú ìdàgbà-sókè bá ojú irin tí ọkọ̀ ń gbà jákè-jádò orílẹ̀-èdè China. Bí ó tilẹ̀ jẹ́ wípé wọ́n ń pè fún ṣíṣe àbójútó tó lọ́ọ̀rìn sí bí ìjàmbá ṣe ń ṣẹlẹ̀ ní ojú òpó àwọn ọkọ̀ ojú-irin. [2] Ní ọjọ́ kẹwàá oṣù kẹta ọdún 2013, wọ́n kéde rẹ̀ wípé wọn yóò tú àjọ náà ká, tí àjọ tí wọ́n ń rí ìgbòkègbodò gbogbo ọkọ̀ ní orílẹ̀-èdè China yóò si ma gba iṣẹ́ wọn ṣe.[3]

Ìtàn ní ṣókí

àtúnṣe

Àwọn àjọ tí wọ́n ti ṣe akóso ilé iṣẹ́ yí rí ni: Qing àti Republican Ministry of Posts and Communications

Bọ́ndì títà

àtúnṣe

MOR, tí wọ́n dúró gẹ́gẹ́ bí àjọ ní ọjà gbèsè, ti ta bọ́ndì tí ó tó mílíọ́nù lọ́nà ọgọ́ta Yuan ní ọdún 2017. MOR tún gbe ro láti ta bóndì tí ó tó ọgbàọ́rùn un kan bílíọ́nù owó Yuan tí ó jẹ́ ($14.6 billion) láti fi fẹ ojú ọ̀na ọkọ̀ ojú irin jákè-jádò ilẹ̀ China ní ọdún 2009.

Àwọn ilé-iṣẹ́ tí wọ́n ní ọkọ̀ akérò ojú irin

àtúnṣe
 
The Wuhan Railway Bureau headquarters

Àwọn àjọ tí wọ́n ń ṣàkóso àwọn ọkọ̀ ojú irin jẹ́ mẹ́rìndínlógún(16) nígbà tí ilé-iṣẹ́ ọlọ́kọ̀ ojú irin tí wọ́n wà ní abẹ́ ilé-iṣẹ́ ìjọba àpapọ̀ fún ìgbòkègbodò ọkọ̀ ojú irin jẹ́ méjì péré. Iye àwọn tí wọ́n ń ṣiṣẹ́ ní abẹ́ ilé-iṣẹ́ yí ní nkan bí ọdún 2098 jẹ́ mílíọ́nù méjì ènìyàn. [2]

Àjọ tàbí ilé-iṣẹ́ tí ó ń rí sí ìgbòkègbodò 9kọ̀ ojú irin ní ẹkùn kọ̀ọ̀kan nìwọ̀nyí
Beijing Railway Bureau Beijing, Hebei, Tianjin, Shanxi(part)
Chengdu Railway Bureau Sichuan, Chongqing
Guangzhou Railway Group Co.,Ltd. Guangdong, Hunan
Harbin Railway Bureau Heilongjiang, Inner Mongolia(part)
Hohhot Railway Bureau Inner Mongolia(part)
Jinan Railway Bureau Shandong,Liaoning(part)
Kunming Railway Bureau Yunnan, Sichuan, Guizhou
Lanzhou Railway Bureau Gansu, Ningxia
Nanchang Railway Bureau Jiangxi,Fujian
Nanning Railway Bureau Guangxi, Guangdong(part)
Qinghai-Tibet Railway Group Co., Ltd. Qinghai, Tibet
Shanghai Railway Bureau Shanghai, Jiangsu, Anhui, Zhejiang
Shenyang Railway Bureau Liaoning, Jilin,Heilongjiang(part),Inner Mongolia(part)
Taiyuan Railway Bureau Shanxi
Wulumuqi Railway Bureau Xinjiang
Wuhan Railway Bureau Hubei
Xi'an Railway Bureau Shaanxi, Gansu, Ningxia,Hubei
Zhengzhou Railway Bureau Hubei(part),Shaanxi, Shandong

Àkójọ àwọn Mínísítà tí wọ́n ti darí àjọ náà nìwọ̀nyí

àtúnṣe
Name Took office Left office
1 Teng Daiyuan October 1949 January 1965
2 Lü Zhengcao January 1965 1966
post abolished
3 Wan Li January 1975 December 1976
4 Duan Junyi December 1976 March 1978
5 Guo Weicheng March 1978 1981
6 Liu Jianzhang 1981 April 1982
7 Chen Puru April 1982 1985
8 Ding Guangen 1985 April 1988
9 Li Senmao April 1988 1992
10 Han Zhubin 1992 March 1998
11 Fu Zhihuan March 1998 March 2003
12 Liu Zhijun March 2003 February 2011
13 Sheng Guangzu February 2011 16 March 2013

Ẹ tún lè wo

àtúnṣe

Àdàkọ:Portal box

Àwọn itọ́ka sí

àtúnṣe
  1. Sui-Lee Wee; Huang Yan; Miral Fahmy (25 February 2011). "China railways minister dismissed -Xinhua". The Los Angeles Times. Reuters. http://www.latimes.com/sns-rt-china-railwaysministoe71o053-20110225,0,1184171.story. [Ìjápọ̀ tí kò ṣiṣẹ́ mọ́]Àdàkọ:Cbignore
  2. 2.0 2.1 Wu, Zhong (May 7, 2008). "Blowing the whistle on 'Big Brother'". Asia Times Online. Archived from the original on May 13, 2008. Retrieved 2008-05-06.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  3. "China scraps railways ministry in streamlining drive". BBC online. BBC. 10 March 2012. https://www.bbc.co.uk/news/world-asia-china-21732566. 

Ìtàkùn ìjá sóde

àtúnṣe


Àdàkọ:Transport in China Àdàkọ:State Council of the People's Republic of China

Àdàkọ:Authority controlỌ̀ṣun