Àndórà tabi fun iseoba o je Ilẹ̀-Ọmọba Andorra, bakanna won tun mo si Ilẹ̀-Ọmọba àwọn Àfonífojì ilẹ̀ Àndórà[1] (Principality of the Valleys of Andorra) je orílẹ̀-èdè aláfilẹ̀yíká ni apa guusuiwoorun Europe.

Principality of Andorra
Ilẹ̀-Ọmọba Andorra
[Principat d'Andorra] error: {{lang}}: text has italic markup (help)
Àsìá
Motto["Virtus Unita Fortior"] error: {{lang}}: text has italic markup (help)  (Latin)
"Strength United is Stronger"
Orin-ìyìn orílẹ̀-èdè[El Gran Carlemany, Mon Pare] error: {{lang}}: text has italic markup (help)  (Catalan)
The Great Charlemagne, my Father

Ibùdó ilẹ̀  Àndórà  (circled in inset) on the European continent  (white)  —  [Legend]
Ibùdó ilẹ̀  Àndórà  (circled in inset)

on the European continent  (white)  —  [Legend]

Olúìlú
(àti ìlú títóbijùlọ)
Andorra la Vella
42°30′N 1°31′E / 42.5°N 1.517°E / 42.5; 1.517
Èdè àlòṣiṣẹ́ Catalan
Orúkọ aráàlú Ará Andorra
Ìjọba Parliamentary democracy and Co-principality
 -  French Co-Prince François Hollande
 -  Episcopal Co-Prince Joan Enric Vives Sicília
 -  Head of Government Antoni Martí
Independence
 -  Paréage 1278 
Ààlà
 -  Àpapọ̀ iye ààlà 468 km2 (196th)
181 sq mi 
 -  Omi (%) 0
Alábùgbé
 -  Ìdíye 2016 77,281 (194th)
 -  2006 census 69,150 
 -  Ìṣúpọ̀ olùgbé 180/km2 (69th)
393/sq mi
GIO (PPP) ìdíye 2005
 -  Iye lápapọ̀ $2.77 billion (177th)
 -  Ti ẹnikọ̀ọ̀kan $38,800 (unranked)
Owóníná Euro (€)1 (EUR)
Àkókò ilẹ̀àmùrè CET (UTC+1)
 -  Summer (DST) CEST (UTC+2)
Àmìọ̀rọ̀ Internet .ad2
Àmìọ̀rọ̀o tẹlifóònù 376
1 Before 1999, the French franc and Spanish peseta. Small amounts of Andorran diners (divided into 100 centim) were minted after 1982.
2 Also .cat, shared with Catalan-speaking territories.

Nínú ètò ìkànìyàn 1995, àwọn tí ó ń gbé Àndórà jẹ́ ẹgbẹ̀rún méjì-dún-láàádọrin (68,000). Àwọn èdè tí ó jẹ́ ti ìjọba níbẹ̀ ni Kàtáláànù tí ìpín ọgọ́ta nínú ọgọ́rùn-ún ń sọ (60%) àti èdè faransé. Wọ́n tún ń sọ Kàsìtílíànù ti àwọn Pànyán-àn-àn gan-an fún òwò àgbáyé àti láti fi bá àwọn tí ó bá wá yẹ ìlú wọn wo sọ̀rọ̀ .ItokasiÀtúnṣe

  1. Funk and Wagnalls Encyclopedia, 1991