Àrùn ọpọlọ
Àrùn Ọpọlọ(tí a ma ùn pe ni "Stroki") jẹ ipo ibajẹ si ọpọlọ to o ma ún selè nitori idilọwọ ipese ẹjẹ (o le jé idinku gidigidi si èjè tó lo si opolo tabi idaduro patapata). Àrùn opolo ma ún yori si ailera awọn iṣan tabi ìropá rosè ni ẹgbẹ kan ara(ole jé apá òtún tàbí ti osi)
Àwon Okùnfà Ewu
àtúnṣe• Isanraju
• Ojọ ogbó
• Otí mímu àpòjù
Ònà Àti Dènà Àrùn
àtúnṣe• Yera fún àjejù iyò [2]
•Idaraya [3]
• yago fun sign [2]
Àwon Itokasi
àtúnṣe- ↑ Ekeh, Bertha; Ogunniyi, Adesola; Isamade, Emmanuel; Ekrikpo, Udeme (2021-06-02). "Stroke mortality and its predictors in a Nigerian teaching hospital". African Health Sciences 15 (1). doi:10.4314/ahs.v15i1.10. PMID 25834533. https://www.ncbi.nlm.nih.gov/pmc/articles/PMC4370132/. Retrieved 2022-02-02.
- ↑ "7 things you can do to prevent a stroke". Harvard Health. 2013-06-01. Retrieved 2022-02-02.
- ↑ "What Can Help Prevent a Stroke?". WebMD. Retrieved 2022-02-02.