Àtòjọ̀ àwọn olórin Highlife ilẹ̀ Nàìjíríà

Àdàkọ:Inc-musongEleyìí ni àtòjọ̀ àwọn olórin Highlife ilẹ̀ Nàìjíríà tí wọ́n gbajúmọ̀ jùlọ ní àtò A - Y. Oríṣiríṣi ẹ̀yà tàbí oníran ìran orin ló wà lórílẹ̀ èdè Nàìjíríà ni èyí tí a ti rí: orin Fújì, Jùjú , Apala, Wéré àti Highlife.[1][2] Bí ó tilẹ̀ jẹ́ pé Ghana ni orini Highlife ti ṣẹ̀ wá tí ó fi tàn dé gbogbo ilẹ̀ Adúláwọ̀ pàạ́́ pàá jùlọ orilẹ̀ èdè Nàìjíríà.[3]

  • Adekunle GoldA
  • Ambassador Osayomore Joseph
  • Dr Sir Warrior
  • Orlando Owoh
  • Oliver De Coque
  • Oriental Brothers
  • Osita Osadebe
  • Rex Lawson
  • Roy Chicago

Ẹ tún lè wo

àtúnṣe

Àwọn ìtọ́ka sí

àtúnṣe
  1. "The Music of Nigeria". World Music Network. Retrieved 15 January 2015. 
  2. "Yorb Music in the Twentieth Century". Retrieved 15 January 2015. 
  3. "BBC NEWS – Africa – Timeline: Ghana's modern musical history". Retrieved 15 January 2015.