Àwọn èdè ní Áfríkà
Ìye àwọn èdè tí wọ́n so ní Áfríkà lé ní ẹgbẹ̀rún méjì,[1] kódà àwọn míràn sọ wípé ó lé ní ẹgbẹ̀rún mẹ́ta.[2] Nàìjíríà nìkan ní tó èdè ẹ̀ẹ́dẹ́gbẹ́ta,(gẹ́gẹ́ bí SIL Ethnologue) ṣe fi léde,[3] Áfríkà jẹ́ ara àwọn ilẹ̀ tí oríṣiríṣi àwọn èdè pò sí jù. Àwọn èdè Áfríkà wá láti oríṣiríṣi ìdílé èdè, àwọn bi:
- Niger–Congo, pẹ̀lú àwọn èdè Atlantic-Congo àti Àwọn èdè Bàntú ní Ìwọòrùn Áfíríkà, Àrin Áfríkà, Gúúsùiìlà oòrùn Áfríkà àti Apágúúsù Áfríkà.
- Àwọn èdè Afroasiatic tí wọ́n sọ ní Ìwọòrùn Ásíà, Àríwá Áfríkà, the Ìwo Orí ilẹ̀ Áfríkà àti apá ibikan ní Sahel.
- Èdè Saharan, Nilotic àti Sudanic tí wọ́n so ní ìlà oòrùn Áfríkà àti ní Sahel.
- Àwọn èdè Austrones tí wọ́n so ní Madagascar àti ní apá Comoros.
- Èdè Khoe–Kwadi tí wọ́n ń sọ ní Namibia àti Botswana.
- Àwọn èdè Índíà mọ́ Europe tí wọ́n ń sọ ní Gúúsù Áfríkà àti ní Namibia.
- (Afrikaans, English, German) and are used as lingua francas in Liberia and the former colonies of the United Kingdom (English), former colonies of France and of Belgium (French), former colonies of Portugal (Portuguese), former colonies of Italy (Italian), former colonies of Spain (Spanish) and the current Spanish territories of Ceuta, Melilla and the Canary Islands and the current French territories of Mayotte and La Réunion.
Àwọn èdè kéékèèké míràn wà tí wọn kò tí ì sì nínú ìdílé kan kan. Àwọn èdè kọ̀kan tún wà ní ilẹ̀ Áfríkà tí wón jẹ́ èdè tí ọ̀pọ̀lopọ̀ àwọn ẹ̀yà ń sọ. Àwọn èdè bi Arabic, Somali, Amharic, Oromo, Igbo, Swahili, Hausa, Manding, Fàtini.
Ààjọ African Union kéde ọdún 2006 gẹ́gẹ́ bi "Ọdún àwọn èdè Áfríkà".[4].
Àwọn Ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ Heine, Bernd; Heine, Bernd, eds (2000). African Languages: an Introduction. Cambridge University Press.
- ↑ Epstein, Edmund L.; Kole, Robert, eds (1998). The Language of African Literature. Africa World Press. p. ix. ISBN 0-86543-534-0. https://books.google.com/books?id=XkkrDH27jmIC&pg=PR9. Retrieved 2011-06-23. "Africa is incredibly rich in language—over 3,000 indigenous languages by some counts, and many creoles, pidgins, and lingua francas."
- ↑ "Ethnologue report for Nigeria". Ethnologue Languages of the World.
- ↑ African Union Summit 2006 Archived 30 May 2006 at the Wayback Machine. Khartoum, Sudan. SARPN.