Ìṣọ̀kan Áfríkà

(Àtúnjúwe láti African Union)

Ìṣọ̀kan Áfríkà (Gígékúrú bí AU ní èdè Gẹ̀ẹ́sì tàbí UA jẹ́ ẹgbẹ́ ìṣọ̀kan tó ní àwọn Orílẹ̀-èdè Olómìnira Adúláwọ̀ márùnléláàádọ́ta (55) bí ọmọ ẹgbẹ́.[Morocco]] nìkan ni orílẹ̀-èdè Olómìnira tí kìí ṣe ọmọ ẹgbẹ́ àjọ Ìṣọ̀kan Adúláwọ̀ . Ìṣọ̀kan Afrikà jẹ́ dídásílẹ̀ ní ọjọ́ Kẹsàn án oṣù Keje, ọdún 2002 (9-7-2002),[8] Àjọ (AU) ni ó kalẹ̀ sí ìlú Addis Ababa, ní orílẹ̀-èdè Ethiopia.

Orin-ìyìn orílẹ̀-èdèLet Us All Unite and Celebrate Together
An orthographic projection of the world, highlighting the African Union and its Member States (green).
Dark green: AU member states
Light green: Suspended states
Political capitalsEthiópíà Addis Ababa
Gúúsù Áfríkà Midrand
Àwọn èdè oníbiṣẹ́ De jure gbogbo àwọn èdè Áfríkà;
de facto Arabic, English, French, Portuguese, Spanish, Swahili[2]
Member States
Àwọn olórí
 -  Ilé Ìgbìmọ̀ Paul Kagame
 -  Ìgbìmọ̀ Jean Ping
 -  Iléaṣòfin Gbogbo Ọmọ Áfríkà Idriss Ndele Moussa
Aṣòfin Ilé Aṣòfin gbogbo ọmọ Áfríkà
Ìdásílẹ̀
 -  Ìwé Àdéhùn Ìdásílẹ̀ OAU 25 May 1963 
 -  Àdéhùn Àbújá 3 June 1991 
 -  Ìkéde Sirte 9 July 2002 
Ààlà
 -  Àpapọ̀ iye ààlà 29,757,900 km2 
11,489,589 sq mi 
Alábùgbé
 -  Ìdíye 2011 967,810,000 
 -  Ìṣúpọ̀ olùgbé 32.5/km2 
84.2/sq mi
GIO (PPP) ìdíye 2010
 -  Iye lápapọ̀ US$ 2.849 trillion[4][5] 
 -  Ti ẹnikọ̀ọ̀kan $2,943.76 
GIO (onípípè) Ìdíye 2019
 -  Àpapọ̀ iye US$2.227 Trillion[6][7]
 -  Ti ẹnikọ̀ọ̀kan $1,681.12 
Owóníná See list
Àkókò ilẹ̀àmùrè (UTC-1 to +4)
Ibiatakùn
au.int
Àmìọ̀rọ̀o tẹlifóònù See list


Àwọn ọmọ ẹgbẹ́Àtúnṣe

Àwọn orílẹ̀-èdè ìsàlẹ̀ wọ̀nyí ni ọmọ ẹgbẹ́ Ìṣọ̀kan Áfríkà:[9]

Fáìlì:Emblem of the African Union.svg
Emblem of the African Union


Àwọn Ìtọ́ka síÀtúnṣe