Àwọn Erékùṣù Kánárì

(Àtúnjúwe láti Àwọn Erékùsù Kánárì)

Awon Erekusu Kanari (pípè /kəˈneəriː ˈaɪləndz/; Spánì: [Islas Canarias] error: {{lang}}: text has italic markup (help), pronounced [ˈizlas kaˈnaɾjas]; 28°06′N 15°24′W / 28.100°N 15.400°W / 28.100; -15.400Coordinates: 28°06′N 15°24′W / 28.100°N 15.400°W / 28.100; -15.400) je awon ile okan ti orile-ede Spain ti won je okan ninu Spanish Agbajo Adaduro ti Spain ati Agbegbe Ode ninu European Union. Ile okan yi budo si eti ariwaiwoorun bebe orile Afrika, 100 km iwoorun bode to fa ija larin Morocco ati Western Sahara. Iwo okun to yapa lati ebado Kanari lo n mo gbe awon oko oju-omi lo si Amerika.[4] Awon erekusu ibe lati eyi to tobijulo si eyi kerejulo ni wonyi: Tenerife, Fuerteventura, Gran Canaria, Lanzarote, La Palma, La Gomera, El Hierro, Alegranza, La Graciosa ati Montaña Clara.

Canary Islands
Islas Canarias
Mount Teide (Tenerife), the highest mountain in Spain. Is also the most visited National Park in Spain.[1][2]
Mount Teide (Tenerife), the highest mountain in Spain. Is also the most visited National Park in Spain.[1][2]
Flag of Canary Islands
Flag
Coat-of-arms of Canary Islands
Coat of arms
Location of Canary Islands
Location of Canary Islands
CountrySpéìn Spain
CapitalSanta Cruz de Tenerife
and Las Palmas de Gran Canaria
Government
 • PresidentPaulino Rivero (CC)
Area
(1.5% of Spain; Ranked 13th)
 • Total7,447 km2 (2,875 sq mi)
Population
 (2009)[3]
 • Total2,098,593
 • Density280/km2 (730/sq mi)
 • Pop. rank
8th
 • Ethnic groups
85.7% Spanish, (Canarian
and Peninsulares), 14.3%
foreign nationals
Demonym
ISO 3166-2
ES-CN
AnthemArrorró
Official languagesSpanish
Statute of AutonomyAugust 16, 1982
ParliamentCortes Generales
Congress seats15
Senate seats13 (11 elected, 2 appointed)
WebsiteGobierno de Canarias

Jeografi

àtúnṣe
 
Map of the Canary Islands

Jeografi adanida

àtúnṣe

Awon erekusu ati awon oluilu won niyi:

Island Capital
Tenerife Santa Cruz de Tenerife
Gran Canaria Las Palmas de Gran Canaria
Lanzarote Arrecife
La Palma Santa Cruz de La Palma
La Gomera San Sebastián de La Gomera
El Hierro Valverde
Fuerteventura Puerto del Rosario
La Graciosa (Lanzarote) Caleta de Sebo