Àwọn ará Kúbà tabi Àwọn eniyan ará Kúbà (Spánì: [Cubanos] error: {{lang}}: text has italic markup (help)) ni awon abugbe tabi omo orile-ede Kuba. Awon olugbe kuba je 12million.Ida mewa je dudu, ida ogun je mollato, ida kan je chinese. awon olugbe kuba ngbe ni 99.6 kilometer per square.

Cubans
Cubanos
Àpapọ̀ iye oníbùgbé
 Kúbà Cuban people (2011)
11,247,925
Total population of Cuba [1]
Regions with significant populations
 Àwọn Ìpínlẹ̀ Aṣọ̀kan (2010/Cuban born) 1,104,679 [2]
 Spéìn (2011) 111,185 [3]
 Itálíà (2008) 15,883 [4]
 Mẹ́ksíkò (2010) 12,108 [5]
 Fenesuela (2001) 9,795 [6]
 Kánádà (2006) 9,395 [4]
 Tsílè (2002) 3,163 [6]
 Argẹntínà (2001) 2,457 [7]
 Swídìn (2008) 2,146 [4]
 Kòlómbìà (2005) 1,459 [4]
 Brasil (2000) 1,343 [6]
 Ẹ̀kùàdọ̀r (2001) 1,242 [6]
 Swítsàlandì (2000) 1,168 [4]
 Nẹ́dálándì (2008) 1,123 [4]
 Ilẹ̀ọba Aṣọ̀kan (2001) 1,083 [4]
 U.S. Virgin Islands (2000) 141 [8]
Èdè

Cuban Spanish

Ẹ̀sìn

Predominantly Roman Catholic
Jewish, Protestant, Santería, irreligious minorities

Asa olugbe Kuba ni orin, ijo ati esin. Awon jews naa gbe ni ibe, won ni ile ta eran ati ile eko fun oj isinmi.Ida ogorin olugbe Kuba ngbe ni igboro, ida ogbon ngbe ni abule. Ida ogoji eto isuna ni won na si ori eko ati ilera won. Ida marun le logorin lo mooko mooka nigbati ida meedogbon ko le ko tabi ka.

Ile eko giga unifasiti to wa ni Kuba je ogota, oluko kan si ogoji olugbe orile -ede naa. Dokita kan si olugbe irinwo ni fun eto ilera won. Ajo World HEalth Organisation fun Orile -ede Kuba gba ami eye Ookan din -ni- ogoji( 39th) ninu igba(200) Public Health System ni odun 2000. Awon ere idaraya ti won man se ni Kuba ni ese jija,ere ori papa,boolu alase ati idije Olimpik.



Itokasi àtúnṣe