Àwọn Ìpínlẹ̀ Mẹ́ksíkò Aṣọ̀kan tabi Mẹ́ksíkò ní sókí jẹ́ orile-ede ni Ariwa Amerika ni Mexico. Ede Panyan-an (Spanish) ni won n so nibe. Apa gusu United State of america ni o wa. awon Panyan-an segun Mexico ni 1519. Mestizos ni pupo ninu awon eniyan ti o wa ni Mexico iyen ni awon ti obi won je apapo Oyinbo ati India. oko ni pupo ninu awonara Mexico ti n sise. 1821 ni ile yii gba ominira leyin opolopo ija. Won di republic ni 1824.

Àwọn Ìpínlẹ̀ Mẹ́ksíkò Aṣọ̀kan
United Mexican States
Mexihco Tlacetililli Tlahtohcayotl;
Àsìá
Orin-ìyìn orílẹ̀-èdè"Himno Nacional Mexicano"
Mexican National Anthem
National seal:
Seal of the United Mexican States Seal of the Government of Mexico.svg
Olúìlú
(àti ìlú títóbijùlọ)
Mexico City
19°03′N 99°22′W / 19.05°N 99.367°W / 19.05; -99.367
Èdè àlòṣiṣẹ́ None at federal level.
Spanish (de facto)
National language Spanish, and 62 Indigenous Amerindian languages[1]
Orúkọ aráàlú Ará Mẹ́ksíkò
Ìjọba Federal presidential republic
 -  President Enrique Peña Nieto
Aṣòfin Congress
 -  Ilé Aṣòfin Àgbà Senate
 -  Ilé Aṣòfin Kéreré Chamber of Deputies
Independence from Spain 
 -  Declared September 15, 1810 
 -  Recognized September 27, 1821 
Ààlà
 -  Àpapọ̀ iye ààlà 1,972,550 km2 (15th)
761,606 sq mi 
 -  Omi (%) 2.5
Alábùgbé
 -  Ìdíye mid-2008 111,211,789 (July - 2009)[2] (11th)
 -  2005 census 103,263,388 
 -  Ìṣúpọ̀ olùgbé 55/km2 (142nd)
142/sq mi
GIO (PPP) ìdíye 2008
 -  Iye lápapọ̀ $1,559 billion[3] (11)
 -  Ti ẹnikọ̀ọ̀kan $14,560[4] 
GIO (onípípè) Ìdíye 2008
 -  Àpapọ̀ iye $ 1,143 billion[5] (13)
 -  Ti ẹnikọ̀ọ̀kan $10,235[4] 
Gini (2008) 46.1[6] (high
HDI (2008) 0.842 (high) (51st)
Owóníná Peso (MXN)
Àkókò ilẹ̀àmùrè Official Mexican Timezones (UTC-8 to -6)
 -  Summer (DST) varies (UTC-7 to -5)
Ìwakọ̀ ní ọwọ́ right
Àmìọ̀rọ̀ Internet .mx
Àmìọ̀rọ̀o tẹlifóònù 52


ItokasiÀtúnṣe

  1. There is no official language stipulated in the constitution. However, the General Law of Linguistic Rights for the Indigenous Peoples recognizes all Amerindian minority languages, along with Spanish, as national languages and equally valid in territories where spoken. The government recognizes 62 indigenous languages, and more variants which are mutually unintelligible.Comision Nacional para el Desarrollo de los Pueblos Indigenas. CDI. México
  2. https://www.cia.gov/library/publications/the-world-factbook/geos/mx.html
  3. CIA World Factbook GDP PPP
  4. 4.0 4.1 "Mexico". International Monetary Fund. Retrieved 2009-04-22. 
  5. Field listing - GDP (official exchange rate), CIA World Factbook
  6. Human Development Report 2007/2008