Èbúté:Ìmọ̀ ìṣirò

OJÚ EWE IMO ISIRO

Ìmọ̀ Ìṣirò jẹ́ èyí t'on jẹ mo nipa ọ̀pọ̀iye (quantity), nipa òpó (structure), nipa iyipada (change) ati nipa ààyè (space). Idagbasoke imo Isiro wa nipa lilo àfòyemọ̀ọ́ (abstraction) ati Ọgbọ́n ìrọ̀nú, pelu onka, isesiro, wíwọ̀n ati nipa fi fi eto s'agbeyewo bi awon ohun se ri (shapes) ati bi won se n gbera (motion). Eyi ni awon Onimo Isiro n gbeyewo, ero won ni lati wa aba tuntun, ki won o si fi ootọ́ re mulẹ̀ pelu itumo yekeyeke.

A n lo Imo Isiro ka kiri agbaye ni opolopo ona ninu Imo Sayensi, Imo Ise Ero, Imo Iwosan, ati Imo Oro Okowo. Bi a se n lo imo Isiro bo si apa eyi ti a n pe ni Iwulo Imo Isiro (Applied Mathematics). Apa keji Imo Isiro ni a mo si Imo Isiro Ogidi. Eyi je mo eko imo isiro to ko ti ni ilo kankan bo tileje pe o se se ki a wa ilo fun ni eyinwa ola.

Awon Orisirisi Nomba ti o wa
  • Nọ́mbà Àkọ́kọ́
  • Nọ́mbà Tódọ́gba
  • Nọ́mbà Tósẹ́kù
  • Nọ́mbà Tíkòsí
  • Nọ́mbà Tósòro
  • Nọ́mbà Apáòsì
  • Nọ́mbà Apáọ̀tún
  • Nọ́mbà Àdábá
  • Nọ́mbà Odidi
  • Nọ́mbà Oníìpín
  • Nọ́mbà Aláìníìpín
  • Nọ́mbà Gidi
  • 'Awon Eka Imo Isiro'
    Eko Isiro Ipilese Imo Isiro Ero Nomba Imo Isiro Onijinle
    Agbeyewo Ninu Imo Isiro Aljebra Alawonile ati Ibamuile Imo Isiro Oniwulo